Ẹ gba bi mo ṣe sọ, wahala awọn Fulani ilu Igangan yoo dopin lọsẹ yii – Alaga ijọba ibilẹ Ariwa Ibarapa

Faith Adebọla Alaga ijọba ibilẹ Ariwa Ibarapa, Ọnarebu Iliasu Ọlọlade Shittu, ti fọwọ sọya pe laarin…

O ṣẹlẹ, awọn Fulani rẹpẹtẹ ti tun ya wọ Igangan, aṣọ bii tawọn Amọtẹkun ni wọn wọ

Faith Adebọla Ko jọ pe iṣoro iwa ọdaran, ijinigbe, ipakupa ati biba ire oko awọn agbẹ…

Awọn obinrin abule Okemiri, niluu Oro, lawọn yoo filu silẹ tawọn Fulani to sa wa lati Igangan ko ba kuro niluu awọn

Awọn obinrin to wa ni abule kan ti wọn n pe ni Okemiri, niluu Oro, nipinlẹ…

Awọn Fulani to sa lọ si Kwara lati Igangan ti tun fẹẹ rija awọn eeyan abule Okemiri to gba wọn lalejo niluu Oro

Stephen Ajagbe, Ilorin Ẹgbẹ kan to jẹ tawọn ọmọ bibi ẹkun Guusu Kwara, iyẹn Kwara South…

Awọn tọọgi kọ lu kọmisanna, wọn tun ṣe awọn mi-in leṣe nibi iforukọsilẹ ẹgbẹ APC n’Iju

Oluṣẹyẹ Iyiade   Ọpọlọpọ eeyan lo fara pa ninu rogbodiyan kan to bẹ silẹ nibi tawọn…

Sunkanmi atawọn ọrẹ ẹ fẹẹ pa Tẹslim, nitori tiyẹn loun ko ba wọn ṣẹgbẹ Ẹyẹ

Ọwọ ọlọpaa ti tẹ awọn janduku ọmọ ẹgbẹ okukun mẹta kan lori pe wọn n fi…

Epo lawọn eleyii n ji ta kọwo Sifu Difẹnsi too tẹ wọn l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko   O kere tan, awọn afurasi ọdaran mẹwaa ni wọn ti n gbatẹgun…

Eeyan mẹtadinlogun jona ku ninu ijamba ọkọ ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin   Eeyan mẹtadinlogun lo jona ku ninu ijamba ọkọ to gbẹmi ogun eeyan…

Awọn aṣaaju Fulani to n gbe lẹyin awọn ọmọ wọn to n huwa ọdaran lo n da wahala silẹ- Seriki Ṣáṣá

Ọlawale Ajao, Ibadan Sarikin Fulani Ṣáṣá, n’Ibadan, Alhaji Haruna Mai Yasin, ti sọ pe awọn aṣaaju…

Amọtẹkun fija pẹẹta pẹlu awọn janduku n’Ibadan, eeyan mẹrin lo dero ọrun

Ọlawale Ajao, Ibadan O kere tan, eeyan mẹrin ni wọn yinbọn pa laduugbo Lalábíran, n’Ibadan, ninu…

Iku pa olori awọn Amọtẹkun kan l’Ọyọọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọkan ninu awọn adari ẹṣọ Amọtẹkun, ẹka ipinlẹ Ọyọ, Ọgbẹni Tajudeen Ìdòwú Salaudeen,…