Wọn ti mu Idris to gun mẹkaniiki pa n’Igbẹsa

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti pada tẹ Bọbọ, ogbologboo ọmọ ẹgbẹ okunkun ti…

Wọn ti tun dana sun agọ ọlọpaa Layẹni, l’Ajegunlẹ

Faith Adebọla O da bii pe agọ ọlọpaa ni awọn ọmọọta to n fa wahala doju…

Ijọba ipinlẹ Eko ti kede konilegbele oni wakati mẹrinlelogun

Lati aago mẹrin ọjọ Isegun, Tusidee, ọsẹ yii, ijọba ipinle Eko ti kede konilegbele kaakiri ipinlẹ…

Awọn ọmọọta dana sun agọ ọlọpaa Apapa-Iganmu

Aderohunmu Kazeem Ni nnkan bii aago mẹsan-an aarọ yii ni awọn ọmọọta kọ lu agọ ọlọpaa…

Ọọni Ileefe rọ awọn ọdọ lati gba alaafia laaye

Ọọni Ile Ifẹ, Ọba Ẹnitan Ogunwusi, ti rọ awọn ọdọ ki wọn gba alaafia laaye, ki…

Ijọba da ṣọja sita l’Ekiti, wọn lawọn fẹẹ fi daabo bo awọn oluwọde ni

Ṣoyẹmi Oluyinka, Ekiti Kọmiṣanna fun eto iroyin ati ilanilọyẹ nipinlẹ Ekiti, Akin Ọmọle, ti sọ pe…

Ọbasanjọ tun gba Buhari nimọran, o lo dara ko ṣe ohun tawọn ọdọ n fẹ

Jide Kazeem Aarẹ orilẹ-ede yii tẹlẹ, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ, ti ke si Muhammad Buhari ko tẹti…

Iwọde SARS: Buhari n ko awọn ṣọja bọ o

*Ṣugbọn awọn ọdọ ni ihalẹ lasan ni Aya awọn eeyan ti n ja bayii o, paapaa…

Nitori iwọde SARS, ijọba ti gbogbo ileewe pa nipinlẹ Eko

Nitori ifẹhonu han to n lọ lọwọ lori SARS, ijọba ipinlẹ Eko ti pasẹ pe ki…

Ọwọ tẹ meji ninu awọn adigunjale to n daamu wọn l’Ogijo

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Meji ninu ikọ adigunjale kan ti wọn n daamu awọn eeyan Ogijo, nipinlẹ…

Awọn ọmọlẹyin Buhari lawọn naa fẹẹ ṣe iwọde tawọn o

Afaimọ ki awọn ọdọ to n ṣewọde lodi si SARS ati awọn ọmọlẹyin Buhari ti wọn…