Lẹyin ti Wasiu tẹwọn de lo tun lọọ ja ọkada gba n’Ipokia

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bi iṣẹ kan ba wa ti ọmọkunrin kan, Wasiu Raji, fẹran lati maa…

Eyi ni bawọn aṣofin Ondo ṣe fẹẹ yọ igbakeji gomina

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Lonii, ọjọ Iṣẹgun,lawọn ọmọ ile igbimọ aṣofin bẹrẹ igbesẹ yiyọ Ọnarebu Agboọla Ajayi…

Baba mi lo nifẹẹ si iṣẹ ṣọja, nitori tiwọn ni mo ṣe wa nileewe naa bayii – Lọọya Kunle

Ọdọmọde ni, nitori ọjọ ori rẹ ko ju mẹẹẹdọgbọn(25), lọ. Ṣugbọn iṣẹ adẹrin-in-poṣonu to n ṣe…

Awọn aṣofin Eko buwọ lu atunṣe eto iṣuna

Faith Adebọla, Eko Ile igbimọ aṣofin ipinlẹ Eko ti ṣagbeyẹwo aba eto iṣuna ipinlẹ naa lakọtun,…

Kayeefi nla! Niluu Ifọn, ara san pa maaluu meje

Fun igba akọkọ niluu Ifọn Ọṣun, maaluu meje ni ara nla to san lasiko ojo nla…

Ondo: Oluwatuyi di akọwe ijọba, bẹẹ ni Ọtẹtubi yoo di kọmiṣanna laipẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Gomina Rotimi Akeredolu tipinlẹ Ondo ti yan akọwe ijọba tuntun, Temitayọ Oluwatuyi. Eyi…

O ṣẹlẹ: Awọn ọtẹlẹmuyẹ mu Magu, ọga EFCC

Ileeṣẹ ọtẹlẹmuyẹ ilẹ yii (DSS) ti mu ọga ajọ to n gbogun ti ṣiṣe owo ilu…

Ijọba Kwara ra awọn ọkọ agbalaisan lati gbogun ti arun korona

Stephen Ajagbe, Ilọrin Lara igbesẹ ijọba lati gbogun ti arun aṣekupani Koronafairọọsi lo mu ki Gomina Abdulrahman…

Ijamba afara Oko-Erin: Gomina ṣabẹwo ibanikẹdun si ẹbi awọn to padanu ẹmi wọn 

Stephen Ajagbe, Ilọrin Ọjọ Abamẹta, Satidee, ọsẹ to kọja, ni Gomina ipinlẹ Kwara, Abdulrahman Abdulrazaq, ṣabẹwo…

‘Aṣigbọ ni, a ko fi gbedeke le ogun Boko Haram’

Ileeṣẹ ọmọ-ogun ofurufu ilẹ yii ti sọ pe aṣigbọ gbaa ni iroyin to jade lanaa lori…

Koronafairọọsi tun ti gbẹmi eeyan meji l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Kọmisanna feto ilera nipinlẹ Ọṣun, Dokita Rafiu Isamọtu, ti kede pe arun koronafairọọsi…