Eeyan mẹrinla mi-in tun ko Korona ni Ọsibitu Ọlabisi Ọnabanjọ, ni wọn ba ti ẹka ayẹwo ibẹ pa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Awọn alaṣẹ Ọsibitu Ọlabisi Ọnabanjọ (OOUTH), ni Ṣagamu, ti tilẹkun ẹka to n…

Ọwọ tẹ wọn o: awọn to n fi ọkada ja foonu gba nIlọrin

Stephen Ajagbe, Ilọrin Ọwọ palaba awọn ọdaran meji, Adam Taofeek ati Alabẹrẹ Adam, ti wọn maa…

Ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ-binrin Eko fẹhonu han lori iwa ifipabanilopọ

Faith Adebọla Ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ-binrin lorileede yii, ẹka ti Eko (Trade Union Congress Women Commission, Lagos…

Nibo lẹyin n gbe, nibo lẹyin wa: Nigba t’Abiọla atawọn eeyan rẹ kọju ija si Awolọwọ ni 1979 (7)

*Idi abajọ ree o Bo ba ṣe pe ko si nnkan kan nibẹ tẹlẹ, ti wọn…

Obinrin to ba bimọ nipinlẹ Ọyọ, oṣu mẹfa ni yoo maa lo nile, ijọba ti fẹẹ fọwọ si i

Bi ijọba ipinlẹ Ọyọ ba fi le mu ileri rẹ ṣẹ, a jẹ pe awọn to…

Ẹni to ba le ri Sunday apaayan to sa nitimọle Ibadan, ẹẹdẹgbẹta ẹgbẹrun Naira lawọn ọlọpaa yoo fun un, nọmba yii ni kẹ́ẹ pe

Awọn ọlopaa ipinle Ọyọ ti kede ni ọsan oni yii pe ẹnikẹni to ba le ṣe…

O ṣoju mi koro (Apa Keji)

Isiaka Akintọla, ori ọkẹrẹ koko lawo, ba a wi fọmọ ẹni a gbọ Nigba ti bata…

O ṣoju mi koro (Apa Kin-in-ni)

Kin ni wahala Lai Muhammed yii gan-an? Ko si ki eeyan ma beere pe kin ni wahala Bọọda Lai Muhammed.…

Awọn alaafaa ti wa lori awọ bayii, nitori Daura, ẹgbọn Buhari, ti ara rẹ ko ya ni

Iroyin to n jade lati ọdọ awọn alagbara ilu Abuja n sọ bayii pe ọgọọrọ awọn…

Baba ti wọn lo fun tẹgbọn-taburo loyun ni awọn obi wọn mọ si i (Fidio)

Iyawo gomina Kwara ti fi Risikatu, obinrin toju rẹ yatọ, sẹnu ikọṣẹ o

Stephen Ajagbe, Ilorin Iyawo gomina Kwara, Olufọlakẹ Abdulrazaq, ti fi Risikatu Abdulazeez, obinrin toju oun atawọn…