Mọto ayọkẹle mẹwaa ati tirela kan jona deeru ninu ọgba ajọ LASTMA l’Oshodi

Faith Adebọla Ina nla kan ti ṣọṣẹ lagbala ajọ to n ri si igbokegbodo ọkọ loju…

O ma waa ga o, wọn tun ṣa iya oniyaa ladaa pa l’Akinyẹle, n’Ibadan

 Ọlawale Ajao, Ibadan Nigba ti ọkan awọn ara Akinyẹle, n’Ibadan, ti balẹ pe ọwọ awọn agbofinro…

Agbọọla Ajayi balẹ gudẹ sinu ẹgbẹ ZLP, o loun lawọn eeyan ipinlẹ Ondo n fẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọjọ Ẹti, Furaidee, ọsẹ yii, ni Igbakeji Gomina ipinlẹ Ondo, Ọnarebu Agboọla Ajayi,…

Iyawo mi fẹẹ fi lilu pa mi o, mi o fẹ ẹ mọ- Gbade 

Ọlawale Ajao, Ibadan “Loootọ ni mo fọ ọkọ mi leti. Oniṣekuṣe ọkunrin ni, ọmọ kan bayii…

Willian balẹ si Arsenal lẹyin ọdun meje ni Chelsea

Oluyinka Soyemi Agbabọọlu Chelsea tẹlẹ, Willian Borges da Silva, ti balẹ si Arsenal lẹyin to tọwọ…

Gomina Dapọ Abiọdun gbesẹ lori ofin konilegbele opin ọsẹ l’Ogun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Oni ọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kẹrinla, oṣu kẹjọ, ni ijọba fopin si konilegbele…

Tọmọde-tagba lo n ṣedaro Dapọ Williams, ọmọ Yoruba daadaa to ku si London

Ilu oyinbo nibẹ lo n gbe, ni London. Ṣugbọn ki i ṣe pe o n gbebẹ…

Ẹyin agbaagba Afẹnifẹre, eti yin meloo?

Mo fẹẹ ya bara diẹ kuro lori eto ti a n ba bọ, ki n lo…

O ma ṣe o, o ku oṣu meji pere ki ọmọbinrin yii ṣeyawo ni mọto pa a lori ọkada

Faith Adebọla Ibanujẹ ti dori agba kodo fawọn mọlẹbi ọmọbinrin arẹwa ti ẹ n wo fotọ…

Awọn adigunjale to yinbọn pa oṣiṣẹ ileepo Akurẹ d’ero ile-ẹjọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Meji ninu awọn adigunjale to yinbọn pa oṣiṣẹ ileepo kan lọjọ kẹtalelogun oṣu…

Ẹ wo Bọọda Tiṣa, o ti rẹwọn he o, ọmọ ọdun mẹwaa lo fipa ba sun l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Tiṣa kan ti wọn porukọ rẹ ni Ọmọtayọ Adanlawọ ti gba idajọ ẹwọn…