Olori awọn aṣofin tẹlẹ, Yakubu Dogara, ti tun kuro ninu PDP, o ti pada si APC

Ni ọjọ Ẹti, Furaidee, ọsẹ yii, ni olori ileegbimọ aṣoju-ṣofin tẹle, Yakubu Dogara, kuro ninu ẹgbẹ…

Adojutẹlẹgan, ọkan ninu awọn oludije, fẹhonu han lori bi Akeredolu ṣe bori ibo abẹle l’Ondo

Olusẹyẹ Iyiade, Akurẹ. Ọkan ninu awọn oludije ibo abẹle ẹgbẹ APC to waye lọsẹ to kọja,…

Ipinlẹ Ogun ni Mumini ti ji owo lanledi rẹ, Oṣogbo lọwọ awọn Amọtẹkun ti tẹ ẹ 

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọwọ awọn ikọ Amọtẹkun ipinlẹ Ọṣun ti tẹ ọmọkunrin kan, Mumini Saheed, ẹni…

O ma ṣe o: Baba Onipuulu yii si binu para ẹ ni Saabo, Eko

Ọkunrin oniṣọọbu puulu (pool) kan, nibi tawọn eeyan ti n ta tẹtẹ ati baba-ijẹbu ninu ọja…

Jẹgẹdẹ ti sọrọ, o ni ki Akeredolu maa ko ẹru ẹ kuro nile ijọba

Ẹni ti ẹgbẹ PDP fa kalẹ lati du ipo gomina ipinlẹ Ondo ninu ibo ti wọn…

Ta ni mọ ọn: Njẹ ẹyin ranti Baba yii bi?

Ẹni ti ẹ n wo yii, Baba Kekere ni wọn n pe e. Baba Kekere ni…

Ohun to fa wahala lasiko ibo ti wọn di ni 1964 niyi o (3)

Ibo ti daru bayii o. Abi nigba to ṣe pe ni alẹ ọjọ ti ibo ku…

Haa, awọn ọlọpaa ti wọn fẹẹ gba ẹgunjẹ si jẹ ki Adisa fi mọto pa obinrin yii

Njẹ ẹ gbọ pe wọn ti pa Stella Okolie, obinrin olukọni kan ni ile-ẹko giga ti…

Eyi lawọn fọto isinku Tolulọpẹ Arotile

Lonii, Ọjọbọ, Tọsidee, ni wọn sinku Tolulọpẹ Arotile, ọmọbinrin afẹronpileeni-jagun akọkọ ninu iṣẹ ọmọ-ogun ofurufu nilẹ…

Emi naa ti gba bẹẹ: Oriire ki i jinna sẹni to ba n ṣe rere

Ki eeyan ṣaa maa ṣe suuru, ko si gbọkan le Oluwa Ọba. Ko si asiko ti…

Nibo lẹyin n gbe, nibo lẹyin wa: Nigba t’Abiọla atawọn eeyan rẹ kọju ija si Awolọwọ ni 1979

*Idi abajọ ree o (3) Oloye Ọbafẹmi Awolọwọ ti sọ pe oun yoo wadii ọrọ ileeṣẹ…