Ẹ woju wọn, awọn ni wọn pa Barakat, ti wọn tun pa alaboyun atawọn mi-in l’Akinyẹle, n’Ibadan

  Titi di ba a ṣe n sọ yii ni gbogbo awọn to wa nibi tawọn…

Ipade alaafia awọn oludije sipo gomina ẹgbẹ APC Ondo fori sanpọn

  Iyiade Oluṣẹyẹ, Akurẹ Afaimọ ki fa-a-ka-ja-a to n fojoojumọ ṣẹlẹ ninu ẹgbẹ oṣelu APC nipinlẹ…

Nitori bi korona ṣe pa ọkan ninu wọn, awọn aṣofin Eko bẹrẹ ayẹwo

  Latari aṣẹ tileegbimọ aṣofin Eko  pa pa pe ki gbogbo awọn ọmọ ile aṣofin naa,…

Nibo lẹyin n gbe, nibo lẹyin wa: Nigba t’Abiọla atawọn eeyan rẹ kọju ija si Awolọwọ ni 1979

*Idi abajọ ree o (2) Afi bii ẹni pe awọn eeyan naa ti ni Oloye Ọbafẹmi…

Eyi ni bawọn aṣaaju Hausa-Fulani ṣe ba Naijiria yii jẹ (9)

Mo n tẹnu mọ ipade ofin ilẹ wa ti wọn ṣe ni ọdun 1950 yii pupọ,…

N’ILE-IFẸ, WỌN NI JUBIRILA J’IYAWO ONIYAWO GBE TỌMỌTỌMỌ

Wọn ti wọ ọkunrin kan to n jẹ Jubril Anifowoṣe lọ sile-ẹjọ ni Ile-Ifẹ o. Lanaa…

Ẹgbọn Tolulọpẹ ti sọrọ o, o ni iku aburo oun ki i ṣoju lasan

Oriṣiiriṣii awuyewuye lo ti n lọ lori iku to pa ọdọmọbinrin kan, Tolulọpẹ Arotile, ẹni to…

Wọn ti yan Yaya Bello gẹgẹ bii alaga igbimọ ti yoo ṣeto idibo abẹle APC nipinlẹ Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Gomina ipinlẹ Kogi, Alaaji Yaya Bello, ni wọn ti kede orukọ rẹ gẹgẹ…

O Ṣoju Mi Koro

Fayoṣe ati Magu ọrẹ rẹ, ṣaago n bu’go Bo ba jẹ aaye gba Ayọdele Fayoṣe ni,…

Ohun to fa wahala lasiko ibo ti wọn di ni 1964 niyi o (2)

“Nibo la oo gbeyii gba! Ki la oo ti ṣeyi si! Ta ni yoo ba wa…

Ẹgbẹ APC kede orukọ awọn oludije to kunju oṣuwọn lati kopa ninu ibo abẹle l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ẹgbẹ oṣelu APC yii ti kede orukọ awọn to kunju oṣuwọn ati kopa…