Koronafairọọsi: Ofin konilegbele n palẹmọ diẹdiẹ l’Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Lalẹ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee to kọja, ni Gomina Kayọde Fayẹmi tipinlẹ Ekiti kede…

Kin ni ero tiyin?

Ṣẹyin naa fara mọ aba ti agba agbẹjọro nni, Aarẹ Afẹ Babalọla, da pe ki wọn…

Laelae, emi o ni i da sọrọ Alaaji atawọn iyawo ẹ mọ o

Alaaji ti n dagba. Fun odidi ọjọ mẹta, ko jade, ere egele toun atawọn iyawo ẹ…

Magaji Nda: Ọtẹ ati jamba ni Alimi fi gba Ilọrin, ki i ṣe Jihaadi

Ẹ ma binu si mi pe mo ya bara kuro lori itan ti a n sọ…

Ọrọ yii ṣi maa dija: Wọn ti gba APC lọwọ Tinubu o

Nigba ti alaga igbimọ awọn gomina ẹgbẹ APC, Atiku Bagudu to tun jẹ gomina ipinlẹ Kebbi…

Olori oṣiṣẹ Gomina Zulum tipinlẹ Borno jade laye

Olori oṣiṣẹ Gomina Babagana Zulum tipinlẹ Borno, Babagana Wakil, ti jade laye. Wakil lo jẹ Ọlọrun…

Ijọba apapọ fi kun owo-epo bẹntiroolu

Ijọba apapọ ilẹ Naijiria ti fi kun owo epo bẹntiroolu, eyi to gbera kuro ni naira…

Awọn ẹruuku tun ya wọ Akinyẹle, n’Ibadan, wọn ṣa iya atọmọ ladaa

Ọlawale Ajao, Ibadan Pẹlu bi awọn ẹni ibi kan ṣe n pa awọn eyan nipakupa lagbegbe Akinyẹle, n’Ibadan, awọn…

Ọwọ tẹ Tọpẹ nibi to ti n fọle onile l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Diẹ lo ku ki wọn dana sun afurasi adigunjale kan, Tọpẹ Owolabi, tọwọ…

Micheal ti wọn sọ pe o payawo atọmọ ẹ n’Ileefẹ ti foju bale-ẹjọ

Michael Adunọla ti fara han niwaju ile-ẹjọ Majisreeti ilu Ileefẹ lori ẹsun pe o pa iyawo…

Ile-ẹjọ sọ awọn ọmọ orileede India meji to n ji epo rọbi satimọle

Faith Adebọla, Eko Afaimọ kawọn ọmọ ilẹ India meji yii, Akash Kumar ati Vishal Guleria ma…