Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Awọn eeyan ti ko mọ Ọgbẹni Ọlasunkanmi Fagbemi ri fẹrẹ le maa…
Author: admin
Awọn araalu binu si Tinubu, nitori bo ṣe ni ki wọn maa fawọn darandaran ni ilẹ ti wọn ko ba lo
Faith Adebọla Titi di asiko yii lawọn eeyan ṣi n fi aidunnu wọn…
Igbakeji gomina Ọṣun ṣabẹwo si abule Wasinmi ti wọn ti pa eeyan mẹfa ninu mọlẹbi kan naa
Florence Babaṣọla Kọmiṣanna ọlọpaa nipinlẹ Ọṣun, Wale Ọlọkọde, ti sọ pe ko si…
Awọn agbebọn tun ko ọmọleewe ati tiṣa lọ ni Kaduna
Faith Adebọla Afaimọ ko ma jẹ pe awọn jaduku agbebọn yii mọ-ọn-mọ doju…
Ọwọ ti tẹ ẹni kan lori ọrọ awọn Fulani mẹfa tawọn agbebọn pa ni Waasinmi
Florence Babaṣọla Ijọba ipinlẹ Ọṣun ti sọ lalẹ ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, lori wahala…
Baba ọmọ to ku lọsibitu FMC, l’Abẹokuta, la aga mọ dokita lori, o ni ko tete tọju ọmọ oun lo fi ku
Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Ko si ọrọ meji tawọn eeyan n sọ nipa ọsibitu Federal Medical Center…
Babade foju bale-ẹjọ l’Ọrẹ, oṣiṣẹ kootu lo lu lalubami
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ondo ti wọ oniṣowo epo kan ti…
Awọn ọmọ ‘Yahoo’ mẹjọ bọ sọwọ awọn EFCC l’Akurẹ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ko din lawọn ọmọ Yahoo mẹjọ ti ajọ EFCC, ẹka tipinlẹ Ọyọ,…
Ibọn meji lawọn ọlọpaa gba lọwọ awọn ọmọ ‘Yahoo’ n’Ilaro
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kejila, oṣu kẹta yii, ni ajọ EFCC mu…
Sanwo-Olu ati Igbakeji ẹ gbabẹrẹ ajẹsara Koro
Faith Adebọla, Eko Gomina ipinlẹ Eko, Babajide Oluṣọla Sanwo-Olu, ti gba abẹrẹ ajẹsara…
Ijọba lawọn o fowo kun owo epo, wọn tọrọ aforiji lọwọ araalu
Faith Adebọla Pẹlu bi aroye ati ariwo ṣe gba igboro kan lẹyin ti ajọ…