Adeleke gbọpa aṣẹ l’Ọṣun

Florence Babaṣọla ati Faith Adebọla Ọjọ pataki ti ọpọ eeyan ti n reti lọjọ Aiku, Sannde,…

Ohun ti Isah ṣe fawọn ọmọleewe ẹ marun-un yii ko ṣee sọ sita o, o buru jai

Faith Adebọla Ẹwọn gbere ti n run nimu afurasi ọdaran kan , Ọgbẹni Umaru Isah, ẹni…

Nnkan de! Sikiru fipa ba ọmọọdun marun-un lo pọ titi to fi ku l’Ogijo

Gbenga Amos, Ogun Eemọ lukutu pẹbẹ lọrọ ọhun, bawọn eeyan ṣe n gbọ ọ ni wọn…

O ma ṣe o, ọkọ tẹ ẹṣọ alaabo oju popo meji pa

Monisọla Saka Oṣiṣẹ ẹṣọ alaabo oju popo ilẹ wa, FRSC meji kan ni wọn ti pade…

Ẹ tutọ ẹ danu, Tinubu o ni i kopa ninu idije ori tẹlifiṣan tabi redio kankan- APC

Faith Adebọla, Eko Ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC), ti ni kawọn to n reti lati…

O dun mọ mi bi Makinde ṣe wa lara awọn gomina marun-un to n tẹle Wike- Ariwoọla

Monisọla Saka Adajọ agba pata nilẹ wa, Olukayọde Ariwoọla, ti i ṣe adajọ agba ilẹ Naijiria…

Bi mo ṣe n wo Tinubu lori tẹlifiṣan lẹnu ọjọ mẹta yii, niṣe laaanu ẹ n ṣe mi– Babachir Lawal

Faith Adebọla Bi ọrọ ti akọwe agbatẹlẹ funjọba apapọ nileeṣẹ aarẹ, Ọgbẹni Babachir Lawal, sọ nipa…

Akọrin ẹmi nni, Sammie Okposo, ku lojiji

Lọla Ojo Akọrin ẹmi to gbajumọ daadaa nni, Sammie Okposo, ti ku o. ALAROYE gbọ pe…

Ile-ẹjọ fagi le idibo ijọba ibilẹ ti wọn di l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Adajọ ile-ẹjọ giga ijọba apapọ to fikalẹ siluu Oṣogbo, Onidaajọ Nathaniel Emmanuel Ayọọla,…

Ọṣun 2022: Adajọ ni dandan ki INEC mu iwe-ẹri Ademọla Adeleke wa

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Onidaajọ Tertsea Kume to jẹ alaga igbimọ to n gbọ ẹsun to ṣu…

Ọwọ awọn ọdẹ ibilẹ tẹ ajinigbe meji l’Ekiti, wọn tun gba owo ti wọn ba lọwọ wọn

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ọwọ agbarijọpọ awọn ẹṣọ ti wọn n sọ ẹnubode ipinlẹ Kogi ati Ekiti,…