Awọn obinrin abule Okemiri, niluu Oro, lawọn yoo filu silẹ tawọn Fulani to sa wa lati Igangan ko ba kuro niluu awọn

Awọn obinrin to wa ni abule kan ti wọn n pe ni Okemiri, niluu Oro, nipinlẹ…

Awọn Fulani to sa lọ si Kwara lati Igangan ti tun fẹẹ rija awọn eeyan abule Okemiri to gba wọn lalejo niluu Oro

Stephen Ajagbe, Ilorin Ẹgbẹ kan to jẹ tawọn ọmọ bibi ẹkun Guusu Kwara, iyẹn Kwara South…

Awọn aṣaaju Fulani to n gbe lẹyin awọn ọmọ wọn to n huwa ọdaran lo n da wahala silẹ- Seriki Ṣáṣá

Ọlawale Ajao, Ibadan Sarikin Fulani Ṣáṣá, n’Ibadan, Alhaji Haruna Mai Yasin, ti sọ pe awọn aṣaaju…

Amọtẹkun fija pẹẹta pẹlu awọn janduku n’Ibadan, eeyan mẹrin lo dero ọrun

Ọlawale Ajao, Ibadan O kere tan, eeyan mẹrin ni wọn yinbọn pa laduugbo Lalábíran, n’Ibadan, ninu…

Iku pa olori awọn Amọtẹkun kan l’Ọyọọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọkan ninu awọn adari ẹṣọ Amọtẹkun, ẹka ipinlẹ Ọyọ, Ọgbẹni Tajudeen Ìdòwú Salaudeen,…

Ẹ wo Daud, Eko lo ti lọọ jale n’Ijẹbu-Ode

Aderounmu Kazeem Ọkunrin yii, Daud James, ti n mura lati lọọ rojọ niwaju adajọ bayii pẹlu…

Kazeem ti dero ẹwọn o, odidi oṣu marun-un lo fi ba ọmọ bibi inu rẹ sun n’Ido-Ọṣun

Florence Babạsọla, Oṣogbo Ọgbẹni Kazeem Ọlapade ladajọ ile-ẹjọ Majisreeti kan niluu Oṣogbo ju sẹwọn lọjọ Ẹti,…

O ma ṣe o! Olukọ Poli Ibadan padanu ẹmi ẹ sinu ijamba ọkọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Inu ọfọ nla lawọn aláṣẹ ati gbogbo olukọ ile-ẹkọ gbogboniṣe ìjọba ipinlẹ Ọyọ,…

Muyideen atọrẹ ẹ ji tẹgbọn-taburo gbe, inu igbo ti wọn so wọn mọ ni wọn ku si l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti tẹ Usman Muyideen ati Isa Memudu lori ẹsun…

Niwọn igba ti ijọba ko ti mu awọn to ti leeyan kuro laduugbo wọn ṣaaju, wọn ko le mu Sunday Igboho-Falana

 Ikilọ ti lọ sọdọ awọn ọlọpaa ilẹ wa latọwọ ajafẹtọọ-ọmọniyan nni, Fẹmi Falana, pe eewọ ni…

Bijọba ba fẹ, wọn le fun Seriki Fulani laaye lọdọ wọn, ṣugbọn ko gbọdọ wọ Igangan mọ – Ọladokun

Faith Adebọla Oludasilẹ ati adari ẹgbẹ awọn ọdọ ilu Igangan, nijọba ibilẹ Ariwa Ibarapa, Ọgbẹni Ọladiran…