Faith Adebọla, Eko Ilumọ-ọn-ka olukọ ẹsin Musulumu lapa Oke-Ọya ilẹ wa, Sheikh Ahmad Abubakar Gumi, ti…
Author: omotanbaje
Ẹya ara ọkọ lawọn eleyii n ji tu ni Surulere tọwọ fi ba wọn
Faith Adebọla, Eko Ẹya ara ọkọ, agaga kinni kan to wa nibi agbari awọn ọkọ ode-oni…
Ọmọọba ran awọn agbanipa si Kabiyesi Ọja-Ọdan
Gbenga Amọs, Ogun Awọn afurasi ọdaran ọmọ ẹgbẹ okunkun mẹfa tọwọ ba lagbegbe Ọja-Ọdan, nipinlẹ Ogun,…
Ọwọ tẹ Ifẹdayọ nibi to ti fẹẹ ji ọmọ meji gbe l’Akurẹ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọwọ ẹṣọ Amọtẹkun ipinlẹ Ondo ti tẹ ọkunrin ọlọkada kan, Ifẹdayọ Oluwadunsin, nibi…
Ikunlẹ abiyamọ o! Fẹnsi ileewe wo pa ọmọde meji l’Amukoko
Faith Adebọla, Eko Awọn ọmọde meji kan, Samat, ọmọọdun mẹsan-an, ati ẹni keji, Saheed, ti wọn…
Ọlọpaa bẹrẹ iwadii lori ọmọ ọdun mọkandinlogun to pokunso niluu Ileṣa
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti bẹrẹ iwadii lori iku ọmọdekunrin ẹni ọdun mọkandinlogun…
O ma waa ga o! Ṣẹgun naa tun fipa ba ọmọ bibi inu ẹ laṣepọ l’Abẹokuta
Gbenga Amos, Ogun Epe rabandẹ rabandẹ lawọn eeyan n gbe baale ile ẹni ọdun mẹrindinlọgọta yii,…
EFCC ti mu oyinbo Chinese to n wakusa lọna aitọ n’llọrin
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ajọ to n gbogun ti iwa jibiti ati ṣiṣe owo ilu mọkumọku nilẹ…
Ẹ wo Oluwaṣeun to n fibọn onike jale n’Idiroko
Gbenga Amos, Ogun Ọjọ gbogbo ni tole, ọjọ kan ni tolohun. O pẹ ti ọdọkunrin ẹni…
Ẹyin ọkunrin gidi da, Ẹniọla Badmus loun n w’ọkọ o
Faith Adebọla, Eko Bawọn apọn ti wọn n wa iyawo, atawọn ọkunrin ti wọn n ṣaroye…
O ma ṣe o, kọntena tẹ ọmọọdun mẹfa pa sibudokọ Iyana Isọlọ
Faith Adebọla, Eko Ọmọ meji, tẹgbọn-taburo, ni baba kan fa lọwọ nigba to n jade nile…