Awọn janduku kọ lu ile Sunday Igboho n’Ibadan

Adewumi Adegoke Ọjọ Aiku, Sannde, ọsẹ yii ni ariwo gba ilu kan pe awọn janduku kan…

Ile alaja mẹta ti wọn n kọ lọwọ da wo l’Ekoo

Jọkẹ Amọri Ile alaja mẹta kan ti wọn n kọ lọwọ to wa ni Akanbi Crescent,…

Makinde yoo kede Olubadan tuntun lọjọ Aje, Mọnde 

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kẹrinla, oṣu keji, ọdun 2022 yii, nijọba ipinlẹ Ọyọ yoo kede ẹni ti…

Nibi tawọn afurasi ọdaran yii fara pamọ si, lọwọ ajọ NSCDC ti tẹ wọn l’Omu-Aran   

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Akolo ajọ ẹṣọ alaabo ṣifu difẹnsi, ẹka ti ipinlẹ Kwara, ni awọn afurasi…

Wọn tun mu tọkọ-taya kan pẹlu ẹya ara eeyan loriṣiiriṣii l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Pẹlu bi ọrọ ọmọ ti wọn ge ori ẹ lati fi ṣetutu owo…

Makinde ṣabẹwo siluu Lanlatẹ, ọgọrun-un miliọnu lo fun ileewe olukọni to wa nibẹ

Faith Adebọla Ṣinkin ni inu awọn araalu, awọn akẹkọọ atawọn alakooso ileewe olukọni (College of Education),…

Wọn ni lasiko ti Saraki n ṣe gomina lo fi dukia ijọba yawo fun ileeṣẹ aladaani rẹ ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Oku ti Senetọ Bukọla Saraki, adari ile aṣofin agba tẹlẹ nilẹ yii sin…

Awọn ọta Oluwoo taṣiiri ẹ, wọn lo fẹẹ gbowo lọwọ gomina fun igbeyawo to fẹẹ ṣe

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Bonkẹlẹ ni Oluwoo, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, kọ lẹta naa, titi di ba a…

Ileeṣẹ ọlọpaa doola eeyan meji lọwọ awọn ajinigbe ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Orin ọpẹ lo gbẹnu awọn arakunrin meji kan, Samuel Faremi ati Emmanuel Adeyẹmi, ti…

Eyi nidi ti Tinubu ko fi le di aarẹ lọdun 2023 – Ighodalo

Oniwaasu agba fun ijọ kan ti wọn n pe ni Trinity House, Lagos, Pastor Ituah Ighodalo,…

Nitori to ba ọrẹbinrin rẹ ṣedanwo, Fasiti Ilọrin le akẹkọọ rẹ kan danu 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Kayeefi lọrọ naa jẹ nigba ti iroyin de si etiigbọ awọn eeyan pe akẹkọọ…