Ijọba Kwara fẹẹ ṣe iwosan ọfẹ fawọn ọmọde 

lbrahim Alagunmu, Ilorin Ijọba ipinlẹ Kwara labẹ isejọba Abdulrahman Abdulrasaq, ti sọ pe, awọn yoo peṣe…

Nitori ikọlu Fulani, awọn gomina ilẹ Yoruba fẹẹ pawọ-pọ lori eto aabo

Ọlawale Ajao, Ibadan Ninu atẹjade ti Gomina ipinlẹ Ondo, Arakunrin Rotimi Akeredolu, fi ṣọwọ sawọn oniroyin…

Awọn agbebọn tu ijokoo igbimọ alaṣẹ Kwara Poly ka n’Ilọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, ni awọn janduku agbebọn ti wọn fura si…

Ilu Arigidi la fẹ ki wọn sin TB Joshua si – Ọba Yisa Ọlanipẹkun

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Zaki ilu Arigi Akoko, Ọba Yisa Ọlanipẹkun, ni awọn ilu ti ranṣẹ ikilọ…

Nitori aabọ owo-osu ti Akeredolu n san, dokita marunlelọgọrun-un binu kọwe fiṣẹ silẹ l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn dokita bii marunlelọgọrun-un ni wọn ti binu kọwe fisẹ silẹ latari aabọ…

Laaarọ kutu Mọnde, awọn obinrin meji ku lasiko ti wọn n lọ sọja l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Idi iṣẹ ẹni la ti n mọ ni lọlẹ lawọn obinrin meji kan…

Adura ati ifọwọsowọpọ wa pẹlu ọga ṣọja ni Naijiria fi le bọ ninu wahala eto aabo – Oluwoo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oluwoo tilu Iwo, nipinlẹ Ọṣun, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, ti ke si gbogbo…

Serikin Fulani lo wa nidii bawọn Fulani ṣe waa paayan rẹpẹtẹ n’Igangan – Aṣigangan

Ọlawale Ajao, Ibadan Aṣigangan tilu Igangan, Ọba Azeez Ọlawuyi, ti sọ pe Sariki Fulani, iyẹn ọba…

 Iru ki waa leleyii, wọn lawọn Fulani to sa kuro n’Igangan ti tun paayan mẹta n’Imẹkọ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta O kere tan, eeyan mẹta ni wọn ku iku ojiji nibi kan ti…

Ọlọkada kan ku l’Oṣogbo, bireeki ọkada rẹ lo ja lojiji

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọkunrin ọlọkada kan la gbọ pe o ti padanu ẹmi rẹ laaarọ ọjọ…

Ọwọ tẹ baale ile mẹrin to ji ẹrọ amunawa MTN n’ Ijoko-Ọta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ṣinkun lawọn ọlọpaa mu awọn baale ile mẹrin yii, Clement Idenyi; ẹni ọdun…