Tọpẹ Alabi dupẹ lọwọ gbogbo awọn ololufẹ ẹ fun aduroti wọn

Faith Adebọla Latari awuyewuye to waye lọsẹ to kọja lori ọrọ abuku to sọ nipa orin…

Ohun kan ṣoṣo ti mo fẹ ni kijọba gbẹsan lara awọn to ṣeku pa ọmọ mi-Iya Ramon

Faith Adebọla Alaaja Salimọt Azeez, iya ọkunrin ẹni ọdun mẹtadinlogoji kan, Ramon Azeez, ti wọn fibọn…

Ajagungbalẹ mẹta ko sọwọ ọlọpaa l’Odogbolu

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bi awọn ọkunrin yii ṣe ti wa ni ahamọ awọn ọlọpaa, lẹka itọpinpin,…

Buhari ni ko si atunto kankan to maa waye, alaimọkan lawọn to n sọ bẹẹ

Faith Adebọla, Eko  Aarẹ orileede wa, Ajagun-fẹyinti Muhammadu Buhari ti ṣi aṣọ loju eegun erongba rẹ…

Wọn yinbọn pa sọrọsọrọ ori redio kan n’Ibadan

Awọn agbebọn kan ti awọn eeyan fura si pe o ṣee ṣe ko jẹ ayakila ti…

Oṣu kẹjọ nigbẹjọ baba ọlọdẹ to pa Kehinde l’Oṣogbo ati pasitọ to gbe ori rẹ fun yoo bẹrẹ

Florence Babaṣọla Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti gbe baba ọlọdẹ kan, Ọgbẹni Adewunmi Gbadamọsi, ẹni ti…

Ọwọ tẹ Abubakar atawọn ọrẹ ẹ ti wọn n ta burẹdi atoogun fawọn ajinigbe

Faith Adebọla Loootọ ni pe bi ina ko ba l’awo, ko le jo goke odo, ọwọ…

Awọn ṣọja ri meje gba pada ninu awọn ọmọọlewe Kebbi ti wọn ji gbe, ọkan ti ku ninu wọn

Faith Adebọla Rẹrẹ run lọjọ Ẹti, Furaidee yii, nigba tawọn ṣọja ilẹ wa lọọ dana ibọn…

Wọn sọ oṣiṣẹ ijọba to gba riba miliọnu marun-un sẹwọn ọdun mejila ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Ile-ẹjọ to ga ju lọ lorileede yii ti ju alaga igbimọ alaṣẹ tẹlẹ…

Tirela Dangote fi oju ọna rẹ silẹ, lo ba tẹ ọlọkada atero pa n’Ibeṣe

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ka ni ọwọ awọn ero ti inu n bi si dẹrẹba kan to…

Pasitọ luyawo ẹ pa, wọn loogun awọro lo fẹẹ fi i ṣe

Njẹ ẹyin gbọ nipa olori ijọ Omega World Global Ministries? Pasitọ Ukachukwu Enoch Christopher, ti ṣọọṣi…