Dapọ Abiọdun ko ọpọlọpọ mọto fawọn ọlọpaa nitori iṣẹ aabo

 Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ko din ni mọto ayọkẹlẹ marundinlogoji (35), ọkọ akero-kẹru ogun (20), ẹwu akọtami…

Awọn olọja ti ṣọọbu pa nitori iwọde ‘June 12’ l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gbogbo awọn ọlọja lo ti gbogbo ṣọọbu wọn pa latari iwọde ‘June 12’…

Ko sohun to le yẹ ẹ, iwọde ‘June 12’ yoo waye-Ẹgbẹ Akẹkọọ

Ẹgbẹ awọn akẹkọọ agbegbe Guusu ilẹ Naijiria, pataki ju lọ ilẹ Yoruba, ti ni ikede ti…

‘June 12’ : Ẹ rin sibi to ba wu yin, a ti pese aabo -Ileeṣẹ ọlọpaa Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Ileeṣẹ ọlọpaa, ẹka ti ipinlẹ Kwara, ti kede pe awọn ti pese aabo…

Maaluu ni Faruq ati Jobo ji gbe tọwọ fi tẹ wọn ni Kwara  

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ẹsọ alaabo (NSCDC) ẹka ti ipinlẹ Kwara ti mu Issa Faruq ati Jobo…

Akin gbe ọrẹbinrin rẹ lọ sile Kabiru, lẹyin to fipa ba a lo pọ tan ni wọn ge e si wẹwẹ l’Apomu

Florence Babaṣọla Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti tẹ Kabiru Ayedun, ẹni ọdun mọkandinlogoji, lori ẹsun…

Lẹyin ti wọn ge ẹya ara Hassana tan ni wọn ju iyooku ara ẹ sẹgbẹẹ ọna ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Ọdọmọbinrin kan torukọ rẹ n jẹ Hassana Muhammad, ni awọn afurasi oloogun owo…

Olukọ meji, akẹkọọ mẹjọ, lawọn agbebọn tun ji gbe nileewe kan ni Kaduna

Faith Adebọla Ibẹrubojo tun ti gbode kan niluu Zaria, pẹlu bawọn janduku agbebọn kan ṣe ya…

Ẹ fun wa laaye lati lo awọn nnkan abalaye lori wahala eto aabo – Awọn ọdẹ

Florence Babaṣọla Agbarijọpọ awọn ọdẹ [local hunters] nipinlẹ Ọṣun, ti rawọ ẹbẹ si Gomina Adegboyega Oyetọla…

Kawọn gomina lọọ yanju eto aabo ipinlẹ wọn, ki wọn yee di gbogbo ẹru le mi lori – Buhari

 L’Ọjọbọ, ọjọ kẹwaa, oṣu kẹfa, ọdun 2021 yii, ni Aarẹ orilẹ-ede wa, Muhammadu Buhari, han lori…

Awọn ọlọpaa ti gbakoso abule tawọn Fulani darandaran ṣakọlu si ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Latari bi awọn Fulani darandaran ṣe ṣakọlu si awọn olugbe ilu Gbabu/Bala, nijọba…