Lẹyin ti wọn gba miliọnu marun-un, awọn ajinigbe tu ara ilu oyinbo ti wọn ji gbe silẹ

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọṣẹ yii, ni Muritala Adebayọ to fi ilu London ṣebugbe…

Raymond ati Ekene gba mọto onimọto l’Ekoo, Ogun lọwọ ti ba wọn 

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta Ọjọ akọkọ ninu oṣu kẹfa yii ko so eso rere fawọn ọkunrin meji…

Eeyan keeyan  ni John yii o, obinrin to wa ṣọọbu lọ sọdọ rẹ lo fipa ba lo pọ ni Sango

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ Aiku, Sannde, ọgbọnjọ, oṣu karun-un, ni ọwọ ba ọkunrin yii, John Daniel,…

Awọn agbebọn ṣa baale ile pa mọnu ile ọti n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Niṣe lawọn ọdaju eeyan pa ọkunrin oniṣowo kan, Ọgbẹni Maduabuchi Linus Onwuamanam nipakupa…

Awọn agbebọn pa ọmọ Magaji Rẹkẹ, nipinlẹ Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Ariwọ ẹkun ati ọfọ lo gba agboole Magaji ilu Rẹkẹ, nijọba ibilẹ Afọn,…

Awọn ajafẹtọọ-ọmọniyan ṣewọde l’Oṣogbo, wọn ni ki Buhari kọwe fipo silẹ

Florence Babaṣọla, Osogbo Agbarijọpọ ẹgbẹ ajafẹtọọ-ọmọniyan nipinlẹ Ọṣun, Osun Civil Societies Coalition, ti ke si Aarẹ…

Nitori ijinigbe: Awọn ọlọkada ipinlẹ Ogun yoo bẹrẹ si i wọṣọ idanimọ

 Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   Pẹlu bi eto aabo ṣe mẹhẹ gidi lorilẹ-ede yii, to si jẹ pe…

Ọwọ tẹ Nasiru to n ṣe bii were ni Saki, aṣe gbọmọgbọmọ ni

Olu-Theo Omolohun, Oke-Ogun Ọwọ palaba ọkunrin kan, Nasiru, ti wọn lo n dibọn bii alarun ọpọlọ,…

Aadọta naira ni baba agbalagba yii fi tan ọmọ ọdun mẹsan-an to fipa ba lo pọ ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Baba agbalagba ẹni ọgọta ọdun, Jerimiah Oyedokun, lọwọ ileeṣẹ aabo ẹni laabo ilu,…

Awọn ọlọpaa ti ṣe Ọmọyele Ṣoworẹ leṣe o, wọn ti gbe e lọ sọsibitu l’Abuja

Faith Adebọla Ọsibitu aladaani kan niluu Abuja ni wọn sare gbe gbajugbaju oniroyin ajafẹtọọ nni, Ọmọyele…

Nitori awọn ajinigbe, ẹṣọ Amọtẹkun fẹẹ maa ṣọ awọn aala ipinlẹ Yoruba

Lati mu ki aabo nipọn si i lawọn ipinlẹ Yoruba, ikọ alaabo Amọtẹkun ti fẹnu ko…