Tirela pada lasiko to n gun biriiji l’Oṣogbo, eeyan mẹjọ lo ku, ọpọ fara pa

Florence Babaṣọla Lasiko ti a n kọroyin yii, eeyan mẹjọ lo ti ku nibi ijamba ọkọ…

Ijọba Eko ni ẹsun mẹrin lawọn maa ka si Baba Ijẹṣa lẹsẹ ni kootu

Faith Adebọla, Eko Ijọba ipinlẹ Eko ti ni faili iwe ẹsun tawọn ọlọpaa lawọn ti fi…

Wọn dana sun afurasi adigunjale pẹlu ọkada rẹ n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin Afurasi adigunjale jale kan pade iku airotẹlẹ lalẹ ọjọ Ẹti, Furaidee, lagbegbe Maraba,…

Eto idibo alaga ibilẹ ati kansilọ yoo waye lọjọ kẹrinlelogun, oṣu keje, nipinlẹ Ogun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Yatọ si iroyin ofege to gbode tẹlẹ nipa akoko idibo sipo alaga ati…

Olowo lawọn eeyan n pe Alaaji Ramọni ni Kwara, aṣe ajinigbe ni, ọpọlọpọ owo ni wọn ka mọ ọn  lọwọ

Faith Adebọla Okoowo jiji eeyan gbe ni ọkunrin kan ti wọn porukọ ẹ ni Alaaji Rahmọni…

Lẹyin ti ọkọ ti tọju ọmọ fun ọdun mẹfa niyawo ṣẹṣẹ sọ pe ale lo ni in l’Ago-Arẹ

Olu-Theo Omolohun Oke-Ogun Ninu oṣu kejila, ọdun 2009, ni Ọgbẹni Adewale Babatunde ṣegbeyawo alarinrin pẹlu Omidan Ashiata Ọmọlọla…

 Iwa ti Baba Ijẹṣa hu buru, o si riiyan lara pẹlu-Abikẹ Dabiri

Faith Adebọla Bi gbajugbaja oṣere onitiata to wa lahaamọ awọn ọlọpaa bayii, Ọlanrewaju James Omiyinka tawọn…

Ẹnikẹni to ba n sọrọ to le mu ki awọn eeyan binu si Buhari yoo ri pipọn oju ijọba -Garba

Faith Adebọla Aarẹ ilẹ wa, Muhammadu Buhari, ti fi aidunnu rẹ han si oko ọrọ ti…

 Nitori ibalopọ, ale da ororo gbigbona si baale ile lara

Njẹ ẹyin gbọ nipa iṣẹlẹ kan to ṣẹlẹ lọsẹ to kọja yii? Ọmọge kan lo diidi…

Iyawo kọ Baba Ibeji silẹ, lo ba gbe majele jẹ l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bo tilẹ jẹ pe ọsẹ to kọja lo ṣẹlẹ, awọn eeyan ko ti…

Ipo adari ilu di wahala n’Ileṣha-Baruba, ọpọlọpọ eeyan lo fara pa

Stephen Ajagbe, Ilorin Ija nla kan bẹ silẹ l’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, lagbegbe Gukonbu/Kpakotoru, niluu Ilesha-Baruba,…