Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọfiisi awọn lọbalọba to wa nile ijọba, l’Oke-Mosan, l’Abẹokuta, ni awọn gomina…
Category: Ìròyìn
Ilé-ẹjọ́ rọ Alájáàwà tilu Àjáàwà loye, wọn lọna eru lo gba depo ọba
Ọlawale Ajao, Ibadan Ile-ẹjọ giga tipinlẹ Ọyọ ti pàṣẹ pé ki Alájáàwà tilu Àjáààwà, ni…
Moshood ti wọn ka ẹya ara-oku mọ lọwọ niluu Gbọngan ti wa lakolo ọlọpaa
Florence Babaṣọla Ọwọ agbarijọpọ awọn ẹsọ alaabo nipinlẹ Ọṣun, iyẹn Joint Tax Force, ti tẹ…
Nitori jibiti miliọnu rẹpẹtẹ ti wọn lu, ogoji ọdun ni tọkọ-tiyawo yii yoo lo lewọn
Ọlawale Ajao, Ibadan Ẹwọn ogoji ọdún nile-ẹjọ sọ tọkọ-tiyawo kan, Ẹbiesuwa Abayọmi Frederick ati iyawo…
Buhari fi Bawa, ẹni ogoji ọdun, ṣe alaga EFCC
Ni bayii, wọn ni opin ti de ba irinajo Ibrahim Magu, ọga agba fun ajọ EFCC,…
Ọlọkada fẹhonu han ni Ṣagamu, nitori ọkan ninu wọn to ku nibi to ti n sa f’agbofinro
Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Ode ro lagbegbe Ṣagamu lọjọ Iṣẹgun, ọjọ kẹrindinlogun, oṣu keji yii, nigba tawọn…
Ṣeyi Makinde atawọn gomina ilẹ Hausa yọju sawọn ọlọja ni Ṣaṣa, wọn lawọn yoo ran wọn lọwọ
Lẹyin wahala buruku to bẹ silẹ niluu Ibadan laarin awọn Hausa/ Fulani atawọn Yoruba lagbegbe Ṣaṣa,…
Saraki atawọn ọmọ ẹgbẹ oṣelu PDP ṣabẹwo si Goodluck Jonathan
Bi ọdun 2023 ti ṣe n sun mọ etile lawọn ẹgbẹ oṣelu ti bẹrẹ oriṣiriiṣii igbesẹ…
Mutiat Adio tun rẹwọn he lẹyin to ti ṣẹwọn lẹẹmeji
Ẹwọn ọdun mẹta ni wọn tun sọ obinrin kan, Mutiat Adio, ti ile-ẹjọ ti kọkọ sọ…
Iwọde Too-geeti: Ẹni to ba fẹẹ ja fun Naijiria gbọdọ mura lati fori la iku – Misita Macaroni
Ọkan pataki ninu awọn to foju wina ibinu awọn agbofinro lọjọ Abamẹta, Satide, ọjọ kẹtala, oṣu…
Dapọ Abiọdun ṣabẹwo si Yewa, o ṣeleri iranwọ fawọn tijamba kan
Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Lọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, ti i ṣe ọjọ kẹẹẹdogun, oṣu keji, Gomina ipinlẹ…