Nitori owo, Kamilu atọrẹ rẹ fẹẹ pa iya arugbo l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla. Oṣogbo Awọn ọdọkunrin meji, Ọlagunju Kamilu ati Adenle Mujeem, ni wọn fara han niwaju…

Awọn ọmọ ẹgbẹ APC tu jade lati ṣeto iforukọsilẹ ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilọrin Yatọ si ohun tawọn eeyan n ro ṣaaju akoko yii pe o ṣee…

Awọn ọmọ ‘Yahoo’ yari n’Ileṣa, wọn ni ki EFCC fi awọn lọrun silẹ

Florence Babaṣọla   Lọwọlọwọ bayii, inu ibẹrubojo lawọn olugbe ilu Ileṣa, nipinlẹ Ọṣun, wa pẹlu bi…

Fani-Kayọde n lo sinu APC, lawon eeyan ba ni alailojuti ni

Faith Adebọla     Latari awuyewuye to gbode kan nigba tawọn eeyan ri minisita feto irinna…

Sanwo-Olu wo awon ile kan ni Banana Island, o ni wọn lufin ijọba

Nitori ti wọn kọle si ibi ti omi le maa gba kọja lawọn eeyan kan ṣe…

Sanwo-Olu kilọ fawọn ọdọ to fẹẹ ṣewọde ta ko ṣiṣi Too-geeti Lẹkki pada

Faith Adebọla Gomina ipinlẹ Eko, Babajide Oluṣọla Sanwo-Olu, ti sin awọn ọdọ to n gbero lati…

Eeyan mẹfa ku, ọwọ tẹ mọkadinlogun, nibi ija awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun ni Dalemọ ati Alakukọ

Kazeem Aderounmu O kere tan, ọmọ ẹgbẹ okunkun mọkandinlogun lọwọ awọn agbofinro tẹ lagbegbe Alakukọ, niluu…

Ijọba lu awọn mọto to lufin irinna ni gbanjo l’Ekoo

Jide Alabi Mọto oriṣiiriṣii bii mẹtalelọgọrin (83) ni ijọba Eko lu ni gbanjo lọjọ Aje, Mọnde,…

Awọn janduku kọ lu oloye ẹgbẹ APC meji nibi ipade kan ni Lafiagi

Stephen Ajagbe, Ilorin Ọrọ di bo o lọ o yago lọna lọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii,…

Nitori Aunty Ramota, ija nla bẹ silẹ laarin Iya Ereko ati oṣere mi-in, ọpẹlọpẹ Mr Latin

Kazeem Aderounmu Fidio kan lo kọkọ wa lori ikanni ẹrọ ayelujara, Instagiraamu ti Jamiu Azeez, ọkan…

Olukọ ileewe giga fi foto obinrin lu oyinbo ni jibiti niluu Ọffa

Stephen Ajagbe, Ilorin Olukọ ileewe giga College of Health Technology, niluu Ọffa, nipinlẹ Kwara, Ọpaṣhọla Abdullahi,…