Eti okun ni wọn ti ri oku Wale lẹyin ọjọ kẹfa to ha sọwọ awọn janduku ni Lẹkki

Faith Adebọla, Eko     Loootọ ni wọn maa n sọ pe ọmọ ẹni ku ya…

Ti Makinde ba gba mi laaye, Wakili, Fulani to dẹrujẹjẹ si wọn lọrun l’Ayetẹ, ko ni i lo ọjọ meji- Sunday Igboho

Ọlawale Ajao, Ibadan Pẹlu bi ọmọ Fúlàní kan ti wọn n pe ni Iskilu Wakili ṣe…

Dapọ Abiọdun ni ki wọn wadii ija Fulani atawọn agbẹ nipinlẹ Ogun

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Ọmọọba Dapọ Abiọdun ti i ṣe gomina ipinlẹ Ogun ti paṣẹ fawọn agbofinro nipinlẹ…

Irọ ni wọn pa mọ mi o… Awujalẹ

 Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Lojiji niroyin kan gbode lọjọ Ẹti, Furaidee,  to kọja yii, pe Awujalẹ ilẹ Ijẹbu,…

Awọn afurasi ọdaran mẹtadinlọgbọn lawọn ọlọpaa ṣa kaakiri Eko

Faith Adebọla, Eko   B’ina o ba tan laṣọ, ẹjẹ o ni i tan leeekanna nileeṣẹ…

Nitori wahala ọrọ ilẹ, ijọba kede konilegbele niluu Ilobu ati Ẹrin-Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ijọba ipinlẹ Ọṣun ti kede konilegbele oniwakati mẹrinlelogun bayii latari wahala to n…

Ki ẹledaa awọn irunmọlẹ da a fun mi, to ba jẹ pe ohun ti mo lọọ ṣe l’Abuja yatọ si ọrọ ilẹ Yoruba-Ọọni

Jide Alabi Wahala buruku lo n ṣẹlẹ laarin awọn ọba alaye meji yii, Ọọni Ile Ifẹ,…

Mi o lọwọ si ikowojọ tawọn eeyan n ṣe nitori  mi- Sunday Igboho

Ọlawale Ajao, Ibadan Akọni ọmọ Yoruba nni, Oloye Sunday Adeyẹmọ,  ti gbogbo eeyan mọ sí Sunday…

Awakọ tirela gba oni-Maruwa lẹṣẹẹ, niyẹn ba ku patapata

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ẹka ti wọn ti n gbọ ẹsun ipaniyan ni ọkunrin kan bayii torukọ…

Awọn tọọgi ya bo ikọ Amọtẹkun at’ọlọpaa n’Ibadan, wọn ṣe mẹrin leṣe ninu wọn

Ọlawale Ajao, Ibadan Ba a ṣe n wi yii, ẹka ti wọn ti n tọju awọn…

Awọn ọdọ yari, wọn lawọn o fara mọ bijọba ṣe fẹẹ ṣi Too-geeti Lẹkki pada bayii

Faith Adebọla, Eko Bawọn ọdọ ṣe n fi aidunnu wọn han si bijọba ṣe n gbero…