Ijọba bẹrẹ iwadii lori ọkọ BRT to gbina lọna Ikorodu

Faith Adebọla, Eko       Ere asadigbolura-ẹni ati akọlukọgba gidi lo waye lọsan-an ọjọ Aje,…

Okonjo-Iweala di obinrin akọkọ nipo ọga agba Ajọ Olokoowo Agbaye (WTO)

Faith Adebọla       Inu ayọ ati idunnu gidi ni minisita feto iṣuna nilẹ wa…

Nitori ẹsun agbere, Ọlatunji gun iyawo ẹ pa l’Owode-Ẹgba

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta   Awọn atẹjiṣẹ to jọ mọ ọrọ ifẹ ti baale ile kan, Ọgbẹni…

Awọn ara ilu Oro ṣekilọ: Ki Fulani ti ko ba kuro niluu wa laarin ọjọ meje fara mọ ohun ti oju rẹ ba ri

Faith Adebọla  Awọn eeyan agbegbe Oro, nijọba ibilẹ Irẹpọdun, nipinlẹ Kwara, ti kede pe gbedeke ọjọ…

Wamuwamu lawọn ọlọpaa duro sawọn ibi kan l’Ekoo, awọn to fẹẹ ṣewọde ni wọn n ṣọ

Jide Alabi     Lati le pinwọ ikojọpọ tabi ṣiṣe iwọde lati fẹhonu han ni Too-geeti,…

Omiṣore darapọ mọ ẹgbẹ APC l’Ọṣun

Florence Babaṣọla Igbakeji gomina ipinlẹ Ọṣun nigba kan, to tun ti figba kan jẹ aṣofin to…

Awọn ẹsọ amọtẹkun gbẹsẹ le maaluu igba (200) to ba oko oloko jẹ n’Irẹsẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ   Awọn maaluu to to bii igba (200) lawọn ẹsọ amọtẹkun ẹka tipinlẹ…

Ki aṣoju tijọba Ogun ran lọ si Yewa too pada dele, Fulani ti tun paayan mẹfa l’Agbọn Ojodu ati Asá

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   A o ti i ko Ifa nilẹ, Ifa ti n ṣẹ, lafiwe…

Nitori owu jijẹ, Beatrice la igi mọ ọkọ rẹ lori l’Okitipupa, lo ba ku patapata

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Owu ajẹju ti mu ki iyawo ile kan, Oueen Beatrice, ran ọkọ rẹ,…

Fulani yii ti jẹwọ o: Emi ataburo mi la ṣeto bi wọn ṣe ji ọga mi ti wọn pa gbe, ẹgbẹrun lọna aadọta naira lo kan mi ninu owo ti wọn gba

Ọlawale Ajao, Ibadan Awọn agba bọ, wọn ni bíkú ile ò ba pa ni, tòde o…

Ọgọfa eeyan ko arun Korona lọjọ kan ṣoṣo l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ   Ọgọfa eeyan ni wọn lo ti ko arun Korona laarin ọjọ kan…