Pasito Kumuyi, olori ijọ Deeper Life, kọ Bibeli tuntun

Olori ati Oludasilẹ ijọ awọn Dipa (Deeper Life) Pasitọ William Kumuyi, ti kọ Bibeli tuntun ni…

Awọn eleyii fipa ba obinrin sun l’Ogijo, wọn tun fidio rẹ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ṣọla Ọlaoluwa, Ibrahim Kẹhinde ati Lukman Banjoko lẹ n wo yii, awọn pẹlu…

Dokita Amẹrika ti ni ki wọn ma sọ pe ko soogun fun korona mọ, oogun ẹ wa o jare

Obinrin oniṣegun oyinbo kan ni orilẹ-ede Amerika, Dokita Stella Emmanuel, ti sọ pe oogun wa fun…

‘Tori pe a ko rẹni ya wa lowo lati ṣowo to wu wa la fi bẹrẹ si i digunjale’

Faith Adebọla, Eko Awọn adigunjale meji yii, Sule Abdulkareem, ẹni ọdun mọkandinlọgbọn, pẹlu ekeji ẹ, Celestine…

Awọn dokita Ekiti yari, wọn ni ijọba ko bikita nipa eto ilera

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ẹgbẹ awọn dokita ijọba nipinlẹ Ekiti, National Association of Government General and Medical Dental…

Nitori ọti amu ju, ile-ẹjọ tu igbeyawo ka ni Ṣaki

Olu-Theo Omolohun, Oke-Ogun Gbogbo oriṣiiriṣii orukọ ti Abilekọ Dorcas pe ọkọ rẹ, Ọgbẹni Akinọla Faleye Samuel, lo…

Korona yoo dohun igbagbe nilẹ wa laipẹ – Ọọni Ogunwusi

Florence Babaṣọla Ọọni ti Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi, Ọjaja 11, ti sọ asọtẹlẹ pe igba…

Ijọba ipinlẹ Ọṣun fagi le Yidi Iasiko Ileya lati dena itankalẹ arun Korona

Akọwe ijọba ipinlẹ Ọṣun, Ọmọọba Wọle Oyebamiji, ti kede pe ko ni i si anfaani fun…

Awọn ọmoleewe to fẹẹ ṣedanwo yoo wọle lọsẹ to n bọ

Awọn ọmọleewe to fẹẹ ṣedanwo oniwee mẹwaa jade ti jagun ajaye o: ijọba ti fun wọn…

Ko siṣẹ lọjọ Alamisi ati ọjọ Jimọ o, nitori ọdun Ileya ni

Ijọba apapọ orilẹ-ede yii ti kede pe ko ni i si iṣẹ ni Ọjọbọ, Tọsidee, ọtunla…

Ta ni yoo pari ija Buhari pẹlu Obasanjọ yii: Wọn o ma darukọ baba soju ọna reluwe kankan

“Ọjọ wo ni ija Buhari ati Ọbasanjọ yoo pari?” Bi ọpọ eeyan ṣe n beere lati…