Awọn dokita Ekiti yari, wọn ni ijọba ko bikita nipa eto ilera

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ẹgbẹ awọn dokita ijọba nipinlẹ Ekiti, National Association of Government General and Medical Dental…

Nitori ọti amu ju, ile-ẹjọ tu igbeyawo ka ni Ṣaki

Olu-Theo Omolohun, Oke-Ogun Gbogbo oriṣiiriṣii orukọ ti Abilekọ Dorcas pe ọkọ rẹ, Ọgbẹni Akinọla Faleye Samuel, lo…

Korona yoo dohun igbagbe nilẹ wa laipẹ – Ọọni Ogunwusi

Florence Babaṣọla Ọọni ti Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi, Ọjaja 11, ti sọ asọtẹlẹ pe igba…

Ijọba ipinlẹ Ọṣun fagi le Yidi Iasiko Ileya lati dena itankalẹ arun Korona

Akọwe ijọba ipinlẹ Ọṣun, Ọmọọba Wọle Oyebamiji, ti kede pe ko ni i si anfaani fun…

Awọn ọmoleewe to fẹẹ ṣedanwo yoo wọle lọsẹ to n bọ

Awọn ọmọleewe to fẹẹ ṣedanwo oniwee mẹwaa jade ti jagun ajaye o: ijọba ti fun wọn…

Ko siṣẹ lọjọ Alamisi ati ọjọ Jimọ o, nitori ọdun Ileya ni

Ijọba apapọ orilẹ-ede yii ti kede pe ko ni i si iṣẹ ni Ọjọbọ, Tọsidee, ọtunla…

Ta ni yoo pari ija Buhari pẹlu Obasanjọ yii: Wọn o ma darukọ baba soju ọna reluwe kankan

“Ọjọ wo ni ija Buhari ati Ọbasanjọ yoo pari?” Bi ọpọ eeyan ṣe n beere lati…

Ẹ woju awọn adigunjale ati babalawo wọn to n daamu awọn eeyan lAbẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ṣinkun lọwọ awọn ọlọpaa ipinlẹ Ogun tẹ awọn adigunjale mẹrin kan ati babalawo…

Ẹfun ree abeedi: Oyediran gun iyawo atọmọ-ọmọ ẹ pa l’Ọṣun

Florence Babaṣọla Kayeefi lọrọ naa jẹ fun gbogbo awọn eeyan ilu Iniṣa, nijọba ibilẹ Odo-Ọtin, nipinlẹ Ọṣun, nidaaji ọjọ Abamẹta, Satide, to…

Oshiomhole jẹwọ: o ni, ọja buruku ni mo ta fẹyin ara Edo ni 2016

Ni gbangba waalia, GRA, ilu Binni ni olori ẹgbẹ APC tẹlẹ, Adams Oshiomhole, ti sọrọ naa…

O ṣẹlẹ: Akpabio ti darukọ awọn aṣofin ti wọn jọ kowo jẹ o

Minisita to n ri si ọrọ agbegbe Niger Delta, Oloye Godswill Akpabio, ti darukọ awọn aṣofin…