Ijọba Dapọ Abiọdun fẹẹ pese BRT fawọn eeyan ipinlẹ Ogun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Gẹgẹ bi ọkọ bọginni akero ti wọn n pe ni BRT ṣe n…

Eeyan marun-un ku ni marosẹ Eko s’Ibadan, ere asapajude lo fa a

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ni nnkan bii aago mẹsan-aabọ aarọ Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, leeyan marun-un (ọkunrin…

Ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ-binrin Eko fẹhonu han lori iwa ifipabanilopọ

Faith Adebọla Ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ-binrin lorileede yii, ẹka ti Eko (Trade Union Congress Women Commission, Lagos…

Akẹkọọ to ni arun Korona kọ idanwo nibudo iyasọta ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Ijọba ipinlẹ Kwara ti ṣeto bi akẹkọọ-binrin ẹni ọdun mẹrindinlogun kan to ni…

Oṣu mẹta ni Kọlade yoo fi dari ọkọ loju titi n’Ilọrin, oyinbo kan lo lu ni jibiti

Stephen Ajagbe, Ilọrin, Fẹsun fifi ifẹ ẹtan lu obinrin oyinbo kan ni jibiti lori ẹrọ ayelujara,…

Ẹ woju awọn Fulani to n da awọn eeyan lọna ni Ṣaki

Olawale Ajao, Ibadan Awọn ero to n ti Ṣaki lọ siluu Igboho lagbegbe Oke-Ogun, ni ipinlẹ…

O ma ṣe o, Buruji Kasamu ku lojiji!

Agbọ-sọgba-nu ni iku ọkan pataki ninu awọn oloṣelu ipinlẹ Ogun, to tun ti figba kan ṣe…

 Ẹ wo Baalẹ to n ba ọmọ bibi inu ẹ sun l’Owode-Yewa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lẹyin ọdun kẹrin to ti n ba ọmọ bibi inu ẹ to jẹ…

Nitori owo itanran ti ko ri san, Fatai para ẹ sawọn TRACE lọrun l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọkunrin kan torukọ ẹ n jẹ Fatai Salami, pa ara ẹ si ileeṣẹ…

Ko pẹ ti Tunde ati Tokunbọ tẹwọn de ni wọn tun lọọ jale l’Oshodi-Oke

Faith Adebọla, Eko Bi ọdọmọkunrin kan, Tunde Ọlaiya, ṣe maa n jade laaarọ, ti yoo wọle…

Kin ni ero tiyin?

Ṣẹyin naa fara mọ aba ti agba agbẹjọro nni, Aarẹ Afẹ Babalọla, da pe ki wọn…