Ọwọ tẹ oṣiṣẹ ileeṣẹ amunawa atawọn marun-un mi-in ti wọn ji ẹrọ tiransfọma gbe l’Abuja

Adewale Adeoye Oṣiṣẹ ileeṣẹ amunawa kan atawọn ọrẹ rẹ marun-un lọwọ ọlọpaa agbegbe Mapape, niluu Abuja, ti i ṣe olu ilẹ wa ti tẹ l’Ọjọbọ, Tọsidee, ọjọ kọkanla, oṣu Kẹrin, ọdun 2024 yii. Ẹsun tawọn agbofinro ọhun fi kan…

O ma ṣe o, kọntena re bọ sori ọkọ ayọkẹlẹ l’Alapẹrẹ, obinrin kan ku loju-ẹsẹ

Faith Adebọla Ogun a-jade-i-wọle ti ja obinrin kan tẹnikan ko ti i mọ orukọ rẹ bayii,…

Nnkan de! Awọn agbegbọn ya wọ sẹkiteriati ijọba ipinlẹ Ọyọ, wọn fẹẹ gbajọba lọwọ Makinde

Ọlawale Ajao, Ibadan Boya ni ọkan Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, yoo ti i balẹ…

Eyi lawọn ohun to ṣẹlẹ ni kootu lasiko igbẹjọ Emefiele ati EFCC

Faith Adebọla Ko sẹni to de ayika ile-ẹjọ giga akanṣe ilu Eko, iyẹn Special Offences Court, to…

Faruq fẹnu kọ lọdọ awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun, ni wọn ba yinbọn pa a n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kwara ti ni awọn ṣi n wa awọn ọmọ ẹgbẹ…

Awọn eeyan ẹkun Guusu ko ni i dibo fun Ayedatiwa, nitori ọdun mẹrin pere ni yoo lo nipo to ba wọle- Odimayọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ. Aṣofin to n ṣoju awọn eeyan ijọba ibilẹ Irele ati Okitipupa, nileegbimọ aṣoju-ṣofin…

Iwaju ita ni ọmọdekunrin yii wa ti wọn fi ji i gbe n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Inu ibanujẹ ati iporuru ọkan ni mọlẹbi ọmọdekunrin kan, Abdulrasheed, ẹni ọdun meji…

 Wọn ti mu Raphael, ọrẹbinrin ẹ lo gun pa

Adewale Adeoye Ọdọ awọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Ozoro, nijọba ibilẹ Isoko North, nipinlẹ Delta, ni gende kan, Ọgbẹni Raphael Egbo, ẹni ogun ọdun, wa. Ẹsun tawọn agbofinro ọhun fi…

Boya lọmọ Naijiria yii yoo pada wale mọ, egboogi oloro ni wọn ka mọ ọn lọwọ ni South Africa

Adewale Adeoye Ninu otẹẹli igbalode kan ti wọn n pe ni Houghton, to wa lagbegbe Johannesburg, lorileede South Africa,…

Emi kọ ni mo ni ọmọ Mohbad o, mo maa gbe awọn to n parọ mọ mi lọ si kootu-Ọba Elegushi

Monisọla Saka Ọba Saheed Ademọla Elegushi, ti i ṣe ọba Ikate Elegushi, nipinlẹ Eko, ti jade…

Awọn afọbajẹ Ibadan fọwọ si Ọlakulẹhin gẹgẹ bii Olubadan tuntun

Ọlawale Ajao, Ibadan Lọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kejila, oṣu Kẹrin, ọdun yii, ni gbogbo awuyewuye to…