Ọpọlọpọ owo, aṣọ ileewe awọn akẹkọọ ati iwe ni wọn ba lọwọ obinrin to n ṣe bii were yii ni n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọbọ, Tọsidee, ọṣẹ yii, lọwọ tẹ obinrin afiniṣowo kan to n dibọn bii…

Iwadii fihan pe ko si aisan kankan lara Adegoke titi to fi ku – Dokita 

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Dokita akọṣẹmọṣẹ nipa ayẹwo si ara oku (Consultant Pathologist), to n ṣiṣẹ pẹlu…

PDP yoo ṣeto idibo abẹle funpo aarẹ ninu oṣu karun-un

Adewumi Adegoke Ti gbogbo nnkan ba lọ bi wọn ti ṣeto rẹ, opin oṣu Karun-un, ọdun…

APC fagi le ipade ọmọ igbimọ ẹgbẹ to yẹ ko waye ni Tọsidee

 Jọkẹ Amọri Ẹgbẹ oṣelu APC ti fagi le ipade awọn ọmọ igbimọ ẹgbẹ naa to yẹ…

‘Biṣọọbu’ fipa ba ọmọ rẹ ati t’aladuugbo wọn lo pọ n’Ipaja, lo ba ni wọn purọ m’oun ni

 Jọkẹ Amọri Niwaju ile-ẹjọ to n ri si ẹsun lilo ọmọ nilokulo ati fifipa ba ọmọde…

Buhari ti sọrọ, o ni Buni ni ko ṣeto idibo gbogbogboo APC

Faith Adebọla Bo tilẹ jẹ pe Aarẹ Muhammadu ko si nile, to jẹ ilu oyinbo lo…

Nitori ọrọ ti ko to nnkan, Soobata gun ọmọ lanlọọdu ẹ pa l’Ondo

Iyiade Oluṣẹyẹ, Akurẹ Titi di ba a ṣe n sọ yii lawọn eeyan ṣi n sọ…

Emi ni ma a kẹsẹ bọ bata Buhari gẹgẹ bii aarẹ Naijiria lọdun 2023-Tinubu

Faith Adebọla Aṣiwaju ẹgbẹ oṣelu APC, Bọla Ahmed Tinubu, ti ṣọ pe oun ko ni i…

Emi ni Telu, mo ga ju Oduduwa ati Awolọwọ lọ – Oluwoo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oluwoo ti ilu Iwo, Ọba Abdulrasheed Adewale Akanbi, ti sọ pe oun ga…

Dandan ni fawọn akẹkọọ wa ni UNIOSUN lati ni imọ nipa iṣẹ ọwọ – Ọjọgbọn Adebooye

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọga agba Fasiti Ọṣun, Ọjọgbọn Clement Ọdunayọ Adebooye, ti sọ pe o pọn…

Nitori aabo to dẹnukọlẹ awọn oloye ilu n beere fun afikun agọ ọlọpaa ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Isẹgun, Tusidee, ọṣẹ yii, ni awọn oloye ọba labẹ Emirate, ke si…