Adajọ ni ki wọn maa ko Kyari atawọn ọmọọṣẹ rẹ lọ si ọgba ẹwọn Kuje

Ọrẹoluwa Adedeji Ile-ẹjọ giga kan niluu Abuja ti paṣẹ pe ki wọn taari Igbakeji kọmiṣanna ọlọpaa…

Ganiyat purọ f’ọkọ ẹ pe oun loyun, lo ba lọọ ji ọmọ ọjọ mẹfa gbe l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọmọbinrin ẹni ogoji ọdun kan, Ganiyat Abass, lo ti n ka boroboro ni…

Emi ni ẹgbẹ APC maa fa kalẹ lati dupo aarẹ lọdun 2023-Yahaya Bello

Jọkẹ Amọri Bo tilẹ jẹ pe agbegbe kan naa ni Abdullahi Adamu ti wọn ṣẹṣẹ yan…

Lẹyin ti David tẹwọn de lo tun lọọ faṣọ ṣọja lu jibiti l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti tẹ ọkunrin ẹni ọdun marundinlogoji kan, Agbebaku…

Tori Ọlọrun, ẹ wo ti aawẹ Ramaddan, ẹ mu adinku ba ọwọngogo ounjẹ yii – Sultan

Gbenga Amos Olori ẹsin Musulumi, Sultan tilu Sokoto, ti parọwa sijọba lati wa nnkan ṣe ni…

Gomina Wike naa fẹẹ dupo aarẹ Naijiria

Jọkẹ Amọri Gomina ipinlẹ Rivers, Nyesome Wike, naa ti fi erongba rẹ lati dupo aarẹ Naijiria…

Awọn adigunjale paayan mẹrin lasiko ti wọn ja oni POS lole n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Iwadii ti bẹrẹ lori bi awọn adigunjale kan ṣe ya wọ adugbo Ladeowo,…

Ọwọ NDLEA tẹ awọn meji to gbe kokeeni, idi marunlelọgọjọ (165) ni wọn ya

Ọrẹoluwa Adedeji Kilogiraamu oogun oloro ti wọn n pe ni kokeeni ti idi rẹ jẹ marunlelọgọjọ…

Eeyan mẹrin ku, mẹtala fara pa, ninu ijamba ọkọ l’Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ko din leeyan mẹrin ti wọn ku, nigba tawọn ero mẹtala tun fara…

Ọwọ ọlọpaa tẹ ṣọja atawọn meji mi-in to ji akẹkọọ yunifasiti gbe l’Ekiti Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti…

Lẹyin ọjọ kẹta ti wọn paayan marundinlogoji, awọn agbebọn tun fẹmi aadọta eeyan ṣofo ni Kaduna

Gbenga Amos  Niṣe lẹjẹ n ṣan bii omi lafẹmọju ọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kẹẹẹdọgbọn, oṣu Kẹta…