Ninu gbogbo awọn oludije sipo aarẹ, emi ni mo kun oju oṣuwọn ju-Amaechi

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Minisita feto igbokegbodo ọkọ nilẹ wa, Rotimi Amaechi, ti ni ninu gbogbo awọn…

Iyansipo Omiṣore yoo le awọn oloṣelu kan wọle l’Ọṣun – Oyetọla

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina ipinlẹ Ọṣun, Alhaji Gboyega Oyetọla, ti sọ pe bi Senetọ Iyiọla Omiṣore…

Kọla, ọmọ MKO Abiọla, fẹẹ dupo aarẹ lọdun 2023

Faith Adebọla, Eko Lẹyin ọdun mejilelogun iku baba rẹ, Kọlawọle, ọmọ bibi agba oṣelu ati oniṣowo…

‘Yahya Bello lo le gbe Naijiria dide, yoo fagba han Tinubu ati Ọṣinbajo’

Monisọla Saka Awọn alatilẹyin ati olupolongo ibo fun Gomina ipinlẹ Kogi to fẹẹ dupo aarẹ Naijiria…

Adigunjale ya wọ ile awọn akẹkọọ Poli Ilaro, wọn ba awọn akẹkọọ-binrin wọn lo pọ

Monisọla Saka Koju ma ribi, gbogbo ara loogun ẹ lawọn akẹkọọ Poli Ilaro fi ọrọ naa…

Tori bi awọn akẹkọọ ṣe fipa ba ẹlẹgbẹ wọn lo pọ, ijọba ti ileewe Chrisland pa l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Ijọba ipinlẹ Eko ti fi agadagodo gbangba sẹnu ọna to wọ ọgba ileewe…

Awọn agbebọn yinbọn pa awakọ nibi to ti n sa fawọn ajinigbe l’Akunnu Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọpọ awọn eeyan ilu Ajọwa Akoko, nijọba ibilẹ Ariwa Iwọ-Oorun Akoko, ni wọn…

Awọn ọmọlẹyin Akeredolu binu sawọn to n gbe iroyin iku rẹ kiri

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ko jọ epe, bẹẹ ni ko jọ aṣẹ, lo n jade lati ẹnu…

Iya mi lo maa n ro mi lagbara nigbakuugba ta a ba fẹẹ lọọ digunjale- Timileyin

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Kayeefi nla lo jọ loju awọn to wa nibi ti ọmọdekunrin ẹni ọdun…

Awọn Fulani kọ lu baba agbẹ ninu oko rẹ n’Ikakumọ Akoko, wọn gun un yannayanna

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Baba ẹni ọdun mẹtadinlọgọrin kan, Alagba Babatunde Benjamin, lori tun ko yọ lọwọ…

Ẹgbẹ APC yoo ṣepade lori eto idibo abẹle wọn ni ogunjọ, oṣu Kẹrin

Monisọla Saka Ẹgbẹ All Progressive Congress (APC), ti fẹnu ko lati pade ni ogunjọ, oṣu Kẹrin,…