Florence Babaṣọla, Oṣogbo Manija ileetura kan niluu Oṣogbo, Joseph Adelẹyẹ, ti n ka boroboro lagọọ ọlọpaa…
Nitori ẹsun ijinigbe, ile-ẹjọ sọ Fulani darandaran mẹfa sẹwọn gbere ni Kwara
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Lọjọ Ẹti, Furaidee, ọṣẹ yii, ni ile-ẹjọ giga kan to fi ilu Ilọrin,…
Ẹ lo anfaani oṣu Ramandan lati gbadura fun Kwara ati Naijiria-Gomina Abdulrazak
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Gẹgẹ bi wọn ṣe kede pe aawẹ awọn Musulumi, iyẹn Ramandan, yoo bẹrẹ…
Wọn ji akẹkọọ gbe ninu ọgba ileewe l’Akurẹ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Akẹkọọ kan lawọn ajinigbe ti ji gbe lọ ninu ọgba ileewe rẹ l’Akurẹ…
Ijọba Eko ṣekilọ: Ẹ fura o, oṣu mẹwaa lojo yoo fi rọ lọdun yii
Faith Adebọla, Eko Bi ko ba ṣe’ni ri, a ki i sọ pe o tun de…
Ẹlẹrii to kẹyin jẹrii gbe Baba Ijẹṣa ni kootu
Faith Adebọla Ẹlẹrii to kẹyin ninu ẹjọ ifipa ba ni lo pọ ti gbajugbaja onitiata ati…
Kayeefi, aara san pa awọn ọdọ marun-un l’Agọọ Dada, Akurẹ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Titi di asiko yii niroyin iku awọn ọdọ marun-un ti aara san pa…
Awọn ọlọpaa ti mu Musa o, iya ẹni ọdun marundinlọgọrin lo fipa ba lo pọ titi tiyẹn fi ku mọ ọn labẹ
Ile-ejọ ni ọmọkunrin kan, Iliya Musa ti ko ju ẹni ọdun mejilelọgbọn lọ, to lọọ fipa…
Ṣe gbogbo yin ti ri idi ti mo ṣe ta ko iyansipo Buhari lọdun 2015 bayii – Fayoṣe
Faith Adebọla “Emi ni mo pariwo ju lọ, ti mo ta ko iyansipo Muhammadu Buhari funpo…
Hassan, ọmọ ọdun mẹtadinlogun, yọ oju Yunusa, o ni oogun afẹẹri loun fẹẹ fi ṣe
Faith Adebọla Bi ki i baa ṣe kọmiṣanna ọlọpaa lo sọrọ ọhun ninu atẹjade to fi…
Oyetọla ni ile-ẹkọ awọn olukọni agba niluu Ileṣa yoo di fasiti laipẹ
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina ipinlẹ Ọṣun, Alhaji Gboyega Oyetọla, ti kede mimu agbega ba ile-ẹkọ olukọni…