Hausa ti lanlọọdu gba sile gun un pa nitori ọrọ ti ko to nnkan n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Titi ta a fi pari akojọpọ iroyin yii ni wọn ṣi n wa…

Ọṣun 2022: Ọmọọba Kọla Adewusi ni yoo ṣe igbakeji Adeleke

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ni imurasilẹ fun idibo gomina ipinlẹ Ọṣun ti yoo waye lọjọ kẹrindinlogun, oṣu…

Ọwọ tẹ iya at’ọmọ, ọmọ ọdun mẹẹẹdogun ni wọn ji gbe pamọ fodidi ọdun mẹta l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ekiti ti kede pe ọwọ awọn ti tẹ iya ẹni…

Andrew Nice, awakọ BRT ti Bamiṣe wọ, loun o jẹbi ni kootu

Faith Adebọla, Eko Ṣe ẹ ranti ọdọmọbinrin ẹni ọdun mejilelogun, Oloogbe Oluwabamiṣe Ayanwọla, to wọkọ BRT…

Ori ko eeyan meji yọ lọwọ ajinigbe n’Idoani, lẹyin ọjọ meji ti wọn ti wa nigbekun wọn

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkunrin kan ti wọn porukọ rẹ ni Idowu Shaba lori ti ko yọ…

Awọn tọọgi pa oṣiṣẹ Operation Burst nitosi Ogbomọṣọ 

Ọlawale Ajao, Ibadan Idarudapọ ṣẹlẹ niluu Iluju, nitosi Ogbomọṣọ, nipinlẹ Ọyọ, pẹlu bi awọn ọdọ agbegbe…

Nitori foonu, Aisha binu da bẹntiroolu sọmọ ẹ lara, lo ba dana sun un ni Mowe

Gbenga Amos, Abẹokuta  Oriṣiiriṣii epe ati eebu lawọn eeyan n rọjo sori ọdaju abiyamọ kan ti…

Iwa ọdaju ati ailaaanu araalu ni bijọba Eko ṣe fẹẹ ṣi too-geeti Lẹkki pada-Bọde George

Adewumi Adegoke Ọkan ninu awọn agbaagba ẹgbẹ oṣelu PDP, Oloye Bọde George, ti sọ pe oun…

‘‘To ba jẹ pe loootọ ni ẹgbẹ PDP fẹẹ rọwọ mu ninu eto idibo aarẹ, iha Guusu/Guusu lo ti yẹ ki wọn fa aṣoju kalẹ’’

Jọkẹ Amọri Ko ti i jọ pe ọrọ ẹni ti yoo dupo aarẹ lorukọ ẹgbẹ oṣelu…

Jan-mọ-ọn mọṣalaaṣi ti mo ti n kirun fun wọn fun iyawo mi loyun-Alaaji Shittu

Ọlawale Ajao, Ibadan Imaamu mọṣalaaṣi kan niluu Ọyọ, Alaaji Lukman Shittu, ti fẹsun kan ọkan ninu…

Awọn ọdọ kan fẹẹ ra fọọmu lati dupo aarẹ fun Tinubu

Jọkẹ Amọri Lati mu ki erongba Aṣiwaju Bọla Tinubu lati di aarẹ Naijiria wa si imuṣẹ,…