Oṣinbajo fẹẹ ṣepade pẹlu gbogbo alaga APC, wọn lọrọ ati dupo aarẹ lo fẹẹ ba wọn sọ

Gbenga Amos  Gẹgẹ bo ṣe wa ninu iwe ipe ti wọn fi ṣọwọ si gbogbo awọn…

NDLEA mu oludasilẹ ijọ pẹlu kokeeni ni papakọ ofurufu Muritala l’Ekoo

Jọkẹ Amọri Isọji ita gbangba ọlọsẹ mẹta ni Oludasile ijọ Christ Living Hope Church, Ugochkwu Ekwem,…

Atẹnujẹ ko ba ọlọkada, obinrin to gbe fun un lọti mu, lo ba gbe ọkada to ṣẹṣẹ ra sa lọ

Ṣe ki Ọlọrun gba ni lọwọ atẹnujẹ ni, ẹni to ba ti n wa ifa, dandan…

Emi o sọ fẹnikan pe ẹya Igbo nipo aarẹ kan lọdun 2023 o – Ọbasanjọ

Gbenga Amos, Abeokuta Olori orileede wa tẹlẹ, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ, ti sọ pe ko si ootọ…

Ọlọpaa bẹrẹ iwadii lori ọkunrin to n fi ọkada jiṣẹ kiri to ti ọmọ mọnu apoti to fi n ko nnkan l’Ekoo

Faith Adebọla Igbaju igbamu ni wọn fi da ọkunrin kan to n fi jiṣẹ kiri niluu…

Dapọ Abiọdun bẹrẹ iwadii lori ile alaja kan to wo paayan meji n’Ipẹru

Gbenga Amos “Ko sẹni to rufin eto ikọle nipinlẹ Ogun ti ko ni i jẹgba ofin.…

Nitori ibẹru awọn agbebọn, araalu tẹ ọmọ meje pa nibi ti wọn ti n sa lọ

Gbenga Amos Giri-giri ẹsẹ ati eruku to n sọ lala ko jẹ ki ẹnikan bikita fẹnikeji…

Ikunlẹ abiamọ o! Eeyan mejila jona ku nibi ijamba ọkọ ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Kwara O kere tan, eeyan mejila lo pade iku ojiji lasiko ti ọkọ Dangote…

Nitori ẹsun ipaniyan, ileeṣẹ ọlọpaa kede pe awọn n wa eeyan meji l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti kede pe ẹbun pataki wa fun ẹnikẹni to…

Nice, awakọ BRT ti wọn lo mọ nipa iku Bamiṣe, ti dero ẹwọn

Faith Adebọla, Eko Ọgbẹni Nice Andrew Omininikoron, ẹni ọdun mẹtadinlaaadọta, awakọ BRT to gbe Oloogbe Bamiṣe…

Ọṣun 2022: Ile-ẹjọ ni Ọmọọba Babayẹmi lofin mọ gẹgẹ bii oludije fun ẹgbẹ PDP

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ile-ẹjọ giga ipinlẹ Ọṣun kan to fikalẹ si ilu Ijẹbu-Jeṣa, ti sọ pe…