Ọlọpaa yinbọn pa meji ninu awọn ajinigbe ti wọn fẹẹ ṣọṣẹ n’Itori

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọjọ Aiku, Sannde ọsẹ yii, ti i ṣe ọjọ kọkandinlọgbọn, oṣu kẹjọ, ni…

Agolo tomato l’Okorie fẹẹ fi gbe egoogi oloro lọ siluu oyinbo tọwọ fi tẹ ẹ l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Wọn ti ni ki gbogbo ẹni to ba mọ nnkan i fi pamọ…

Biṣọọbu Oyedepo fi awọn to n ni Naijiria lara gegun-un buruku

Faith Adebọla, Eko Ilu-mọ-ọn-ka ajihinrere ati olori ijọ Living Faith Church Worldwide, tawọn eeyan mọ si…

Ohun eelo ti wọn yoo fi dana ounjẹ lọmọ iya meji n lọọ ra ti aara fi san pa wọn l’Ọṣun

Florence Babaṣọla Ṣe ni jinnijinni da bo gbogbo awọn olugbe agbegbe Oriṣa Ẹlẹjin, niluu Ikirun, nipinlẹ…

Ọwọ tẹ afurasi meji lori iṣekupani to waye ni Mọdakẹkẹ

Florence Babaṣọla Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti sọ pe afurasi meji lọwọ ti tẹ lori wahala…

FIDIO:OMỌ ALE YORUBA NI YOO SỌ PE OUN KO FARA MỌ KA DA DURO

Wọn pa ọmọ sẹnetọ ilẹ wa sinu ile ẹ, niṣe ni wọn yin in lọrun pa

Inu ibanujẹ nla ni ọkan ninu awọn sẹnetọ ilẹ wa lati ipinlẹ Kebbi, Bala Na Allah,…

Awọn agbebọn ya wọ otẹẹli kan ni Kwara, wọn ji Aminu gbe, wọn si yinbọn pa Rasak

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Egbinrin ọtẹ, bi a ṣe n pa ọkan ni omiiran n ru ni…

Wọn ni ileeṣẹ apinna-ka fẹẹ fi kun owo ina ijọba, ṣugbọn awọn eeyan naa ni irọ ni

Jọkẹ Amọri Bi wọn ko ba yi ipinnu wọn pada, a jẹ pe afikun yoo ba…

  Awọn agbebọn tun paayan marun-un mi-in ni Mọdakẹkẹ

Jọkẹ Amọri Iroyin to tẹ wa lọwọ ni pe wọn ti tun pa eeyan marun-un mi-in…

Iyawo to gun ọkọ ẹ pa lọdun keje sẹyin gba ominira lọgba ẹwọn

Ọmọbinrin kan, Rahma Hussein, ko ju ọmọ ọdun mẹrindinlogun (16) lọ lọdun 2014 ti wọn fa…