Korona pa Adegbọla, alaga ẹgbẹ PDP l’Ekoo

Jọkẹ Amọri  Titi di ba a ṣe n sọ yii ni awọn ọmọ ẹgbẹ oṣelu PDP…

Aye ti bajẹ o, wọn ba ori eeyan mẹta ninu firiiji ni yara agbabọọlu kan

Ọdọmọkunrin  agbabọọlu kan ti orukọ rẹ n jẹ Richard Gyamfi yoo rojọ gidi ko too le…

Ki Aarẹ Bahari ma fipa sọ ilẹ awọn ẹni ẹlẹni di aaye ijẹko-Tambuwal

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Nitori aba kan ti igbimọ to n ri si ọrọ ifẹranjẹko lorilẹ-ede yii…

Ikọlu ileewe awọn ologun: Buhari fẹẹ sọ Naijiria di Afghanistan ni o-SOKAPU

Awọn eeyan agbegbe Iwọ Oorun Kaduna ti wọn n pe ni Southern Kaduna Peoples Union ti…

Ogbologboo ni Taiwo yii o, laarin wakati mẹjọ lo yi awọ Toyota Camry to ji n’Ilọrin pada si dudu

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ajọ ẹsọ alaabo ṣifu difẹnsi, ẹka ti ipinlẹ Kwara, ti mu ọkunrin kan…

Awọn agbebọn tun paayan marundinlogoji ni Jos

Jọkẹ Amọri Ni nnkan bii aago mẹsan-an alẹ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii, ni awọn agbebọn…

Awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun ṣa Quadri pa l’Oṣogbo

 Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun sọ pe awọn ti bẹrẹ iwadii lori bi awọn…

Ki i ṣe aisan kindinrin lo n ṣe Ọlaiya Igwe-Owolabi Ajasa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Latari iṣẹ abẹ ti agba oṣere nni, Ẹbun Oloyede tawọn eeyan mọ si…

”A ti n ṣiṣẹ pọ pẹlu awọn ẹṣọ alaabo lati doola akẹkọọ fasiti ti wọn ji gbe ni Kwara”

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Awọn alaṣẹ ileewe giga Fasiti KWASU ti fi gbogbo awọn akẹkọọ to n…

O ma ṣe o, arun Korona pa eeyan mẹta l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ibẹru-bojo ti gba ọkan awọn eeyan nipinlẹ Ekiti pelu bi Kọmiṣanna fun eto…

Oku iya to bi i ni Bọla waa ṣe ni Naijiria latilu oyinbo, ni wọn ba yinbọn pa a ni marosẹ Eko s’Ibadan

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Boya Bọlanle Aworetan Ọmọjuwa ko ba mọ ko ma wale, iba jẹ pe…