Adajọ da ẹbẹ Malami lati ma gbọ ẹjọ Sunday Igboho nile-ẹjọ ipinlẹ Ọyọ nu

Jọkẹ Amọri L’Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii, ni ile-ẹjọ giga kan to jokoo niluu Ibadan, nipinlẹ Ọyọ,…

Awọn adigunjale kọ lu ọkọ agboworin l’Emure

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọlọpaa kan la gbọ pe o fara gbọta lasiko tawọn adigunjale ṣe akọlu…

Ọdun Iṣẹṣẹ: Gomina Oyetọla kede ọjọ Ẹti gẹgẹ bii isinmi lẹnu iṣẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina ipinlẹ Ọṣun, Adegboyega Oyetọla, ti kede ọjọ Ẹti, Furaidee, to n bọ,…

ỌMỌ NAIJIRIA Ẹ GBA MI O, MI O KI I ṢE IYA AJẸ O, WỌN FẸẸ FI BA MI LORUKỌ JẸ NI

Muiz Banirẹ ṣabẹwo si Tinubu ni London

Jokẹ Amọri Gbajumọ agbẹjọro to ti figba kan jẹ kọmiṣanna fun igbokegbodo ọkọ nipinlẹ Eko, to…

Iwadii bẹrẹ lori ọkọ gbajugbaja pasitọ to pokunso l’Ondo

Jọkẹ Amọri Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ondo ti fidi ẹ mulẹ pe loootọ ni baba kan, Lasisi…

Ọmọ ẹgbẹ okunkun mẹsan-an bọ sọwọ ọlọpaa n’Ibadan, akẹkọọ poli wa ninu wọn

Jọkẹ Amọri Ko din ni ọmọ ẹgbẹ okunkun Ẹyẹ mẹsan-an ti Kọmandi ọlọpaa to wa ni…

  Awọn ọdọ ṣewọde lọ sileejọba n’Ibadan, nitori Ọpẹyẹmi ti wọn ni ẹṣọ Amọtẹkun pa

Jọkẹ Amọri Titi di asiko ta a fi pari iroyin yii ni awọn ọdọ ti ko…

A ko ni i yọ owo iranwọ lori epo bẹntiroolu lai ṣepade pẹlu ẹgbẹ oṣiṣẹ-Ijọba Apapọ

Lati ma mu inira ba awọn araalu ni ijọba apapọ fi ni aọn ko ti i…

Nitori ai tẹle ofin ile kikọ, ijọba Ogun ti ile mẹrindinlọgbọn pa ni Mowe

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ko din ni ile mẹrindinlọgbọn ati ileeṣẹ ijọba ipinlẹ Ogun, labẹ akoso ileeṣẹ…

Buhari gbe igbimọ ti yoo ṣe amulo ofin tuntun lori ọrọ-epo bẹntiroolu kalẹ

Joke Amọri Ninu atẹjade kan ti Oludamọran Aarẹ lori eto iroyin, Ọgbẹni Fẹmi Adeṣina, fi sita…