Awọn agbebọn yii laya o, ilu abinibi gomina Zamfara ni wọn ti lọọ ji ọmọleewe rẹpẹtẹ gbe lọsan-an gangan

Faith Adebọla Kaka ki ewe agbọn dẹ, koko lo n le si i lọrọ awọn janduku…

Nitori ẹsun jibiti, adajọ sọ akẹkọọ Kwara Poli ati akẹgbẹ ẹ sẹwọn n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọṣẹ yii, nile-ẹjọ giga kan niluu Ilọrin, nipinlẹ Kwara, sọ…

Ko ti i ju oṣu mẹjọ lọ ti mo bẹrẹ iṣẹ jija foonu gba, Emeka ni mo maa n ta a fun n’Ikẹja-Balogun

Faith Adebọla, Eko  Ọlajide Balogun lorukọ ọkunrin ẹni ọdun mẹrindinlogoji to wa ninu fọto yii, ọmọ…

Ijọba o gbọdọ fun ẹnikẹni labẹrẹ ajẹsara Korona ni tipatipa-Ile-ẹjọ lo sọ bẹẹ

Faith Adebọla Ile-ẹjọ giga apapọ kan to fikalẹ siluu Port-Harcourt, nipinlẹ Rivers, ti sọ pe ọrọ…

Buhari le awọn minisita meji danu, o yan awọn mi-in dipo wọn

Faith Adebọla  Meji lara awọn minisita to n ba ijọba apapọ ṣiṣẹ, Minisita lori feto ọgbin,…

Nitori tọkọ-tiyawo ti wọn ji gbe, awọn eeyan fẹhonu han l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ni kutukutu owurọ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii, ni awọn ajinigbe tun ji…

Awo ounjẹ lọmọọdọ yii fọ, lọga ẹ ba fipa rọ ata si i lọfun

Faith Adebọla Obinrin kan ti wọn porukọ ẹ ni Ojuigo David ti wa lahaamọ awọn ọlọpaa…

 Kootu gbẹsẹ le apo ikowosi ati ile Bidemi Rufai, ọmọọṣẹ Dapọ Abiọdun tẹlẹ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ile-ẹjọ giga kan nipinlẹ Eko ti gbẹsẹ le apo ikowosi Abidemi Ganiu Rufai,…

Awọn agbebọn ṣeku pa olori awọn Fulani labule kan ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Awọn agbebọn ti ṣeku pa olori awọn Fulani, Alhaji Alhaji Sheidu Madawaki, labule…

Nitori bi eto aabo to dẹnukọlẹ, ijọba ṣepade pẹlu awọn adari Fulani ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Gomina ipinlẹ Kwara, Abdulrahman Abdulrazaq, ti ṣepade pẹlu awọn adari Fulani nipinlẹ naa…

Ọwọ ọlọpaa tẹ Fulani ajinigbe meji, wọn pa ọkan, wọn mu ekeji laaye n’Imala

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokutan Niṣe lo jọ pe awọn ajinigbe atawọn ọlọpaa ti jọ pinnu pe awọn…