Awọn aṣofin Eko yọ alaga kansu mẹta nipo, wọn larufin ni wọn

Faith Adebọla, Eko Ile-igbimọ aṣofin Eko ti fọwọ osi juwe ile fawọn alaga ijọba ibilẹ mẹta…

Awọn aṣọbode atijọba n fi ayẹwo Korona lu wa ni jibiti ni o – Kunle Afọlayan

Faith Adebọla  Gbajugbaja oṣere tiata ilẹ wa kan, Ọgbẹni Kunle Afọlayan, ti pariwo pe bii ẹni…

Iṣẹ ni ọmọkunrin yii fi tan akẹkọọ-jade fasiti, to si pa a sinu igbo lẹyin to fipa ba a lo pọ tan

 Faith Adebọla Agba adura ni ti wọn ba n sọ pe ‘a n wa ohun ti…

Ọwọ ọlọpaa tẹ Kẹhinde pẹlu ori ati ọwọ eeyan l’Ajaṣẹ-Ipo, o loun fẹẹ fi ṣoogun owo ni

Stephen Ajagbe, Ilọrin Ọdọmọkunrin kan, Kẹhinde John Moses, ti ha sọwọ awọn ọlọpaa nipinlẹ Kwara, nitori…

A maa ṣe iwọde tawọn ọlọpaa ko ba fun Baba Ijẹṣa ni beeli tabi ki wọn gbe e lọ sile-ẹjọ-Yọmi Fabiyi

Ọkan pataki ninu awọn oṣere ilẹ wa, Yọmi Fabiyi, ti sọ pe awọn maa ṣe iwọde…

Fulani tun ji awọn mẹta n’Igangan, miliọnu mẹwaa ni wọn n beere

Faith Adebọla, Eko Bi kii ba ṣe ori to ko ẹni kẹrin yọ, to fi raaye…

Ọwọ tẹ adigunjale mẹwaa ati Idris to n ṣe baba isalẹ wọn n’Ikẹja

Faith Adebọla, Eko Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ni awọn ti tun iṣẹ to, awọn ti n…

Latari ẹsun ifipabanilopọ ti wọn fi kan an, Baba Ijẹṣa padanu iṣẹ olowo nla

Faith Adebọla, Eko Adanu n gori ibanujẹ ni lasiko yii fun gbajugbaja oṣere tiata ilẹ wa…

Awọn iwa Buhari lẹgbẹ Afẹnifẹre fi kọ lati ṣatilẹyin fun un lasiko idibo to kọja -Faṣọranti

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Olori ẹgbẹ Afẹnifẹre, Oloye Reuben Faṣọranti, ti ni ọkan-o-jọkan iwa ibajẹ pẹlu eto…

Awọn ọlọpaa ṣi n wa Roselyn at’alejo ẹ tawọn kan ji gbe l’Ọfada

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Titi ta a fi pari akojọpọ iroyin yii ni awọn ọlọpaa ipinlẹ Ogun…

Ẹgbẹrun marundinlọgọta naira la maa san fun oṣiṣẹ to kere ju lọ l’Ekoo – Sanwo-Olu

Faith Adebọla, Eko Atẹwọ ayọ rẹpẹtẹ lo rọjo lọjọ Abamẹta, Satide yii, nibi ayẹyẹ ayajọ awọn…