Ijọba lawọn o fowo kun owo epo, wọn tọrọ aforiji lọwọ araalu

Faith Adebọla     Pẹlu bi aroye ati ariwo ṣe gba igboro kan lẹyin ti ajọ…

Olubadan ti sọrọ o: Abẹ akoso Baalẹ Ṣaṣa ni Seriki Ṣaṣa wa

Faith Adebọla Olubadan tilu Ibadan, Alayeluwa Ọba Saliu Adetunji, ti ṣalaye ipo akoso ilu Ṣaṣa, niluu…

Ile-ẹjọ to ga ju lọ fontẹ lu ẹwọn ọdun mẹwaa fun Joshua Dariye

Faith Adebọla, Eko  Boya ni gomina ipinlẹ Plateau tẹlẹ, Ọmọwe Joshua Dariye, le gbagbe ọjọ Ẹti,…

Agbebọn tun ji awọn ọmọleewe obinrin ko ni Kaduna

Faith Adebọla  Ojumọ kan, iṣẹlẹ kan, lọrọ awọn agbebọn ti wọn n ji awọn akẹkọọ gbe…

Iya ọlọmọ meji ku nibi ti oun ati ọrẹkunrin ẹ ti n ṣere ifẹ

Titi dasiko yii ni ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Adamawa ṣi ti ọkunrin kan, Lekan Agboọla, mọ ẹyin…

Mi o le da iyawo mi mu ni mo ṣe la ọmọ-odo mọ ọn, mi o mọ pe o maa ku- Christoher

Christopher Chiabata lọkunrin yii n jẹ, ẹni ọdun mẹrindinlọgọta( 56) ni. Atimọle lo wa bayii, lọdọ…

Awọn ọlọpaa gba mọto lọwọ mi lọna eru, wọn si ta a fun ọkan lara wọn – Kọlawọle

Florence Babaṣọla   Ọgbẹni Elusanmi Kọlawọle fara han niwaju igbimọ to n ṣewadii iwa awọn ọlọpaa…

Akẹkọọ fasiti Al-Hikmah lẹdi apo pọ pẹlu agunbanirọ lati ja ileewe naa lole miliọnu mẹsan-an naira

Stephen Ajagbe, Ilorin Akẹkọọ kan to wa nipele 400Level, ni fasiti Al-Hikmah, niluu Ilọrin, Idris Shuaibu…

Ọlọpaa meji padanu ẹmi wọn ninu ijamba ọkọ lọna Ilọrin si Ogbomọṣọ

Stephen Ajagbe, Ilorin   Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, nijamba ọkọ gbẹmi ọlọpaa meji lagbegbe Ẹyẹnkọrin, lọna…

Wasiu Ayinde, gbajugbaja onifuji, ti ku o

Ọlawale Ajao, Ibadan   Agba ọjẹ lagbo ere Fuji, Alhaji Wasiu Salawudeen Gbọlagade Ayinde, ti jade…

Awọn agbanipa yinbọn fun Ridwan Oyekọla, ọmọ Yorùbá to mọ ẹ̀ṣẹ̀ ẹ já jù lagbaaye

Ọlawale Ajao, Ibadan   Ori lo ko abẹ́ṣẹ́-kù-bíi-òjò nni, Ridwan Oyekọla, ọdọmọde to n ṣoju orileede…