Gani Adams, Sunday Igboho atawọn OPC fẹẹ ṣewọde ta ko maaluu jijẹ nilẹ Yoruba

Bi gbogbo nnkan ba lọ bo ṣe ye, ọjọ Ẹti, Furaidee, ọsẹ yii, ni Aarẹ Ọnakakanfo…

Ọwọ ba Sugar ati Stainless ni Mushin, ibọn ni wọn fi n digunjale

Faith Adebọla, Eko Awọn afurasi adigunle meji kan, Quadri Ayọnuga ti inagijẹ rẹ n jẹ Ṣuga,…

 Olugbenga Ale di olori awọn oṣiṣẹ l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade Akurẹ Gomina ipinlẹ Ondo Rotimi Akeredolu ti kede Ọgbẹni Richard Ọlabọde Ọlatunde gẹgẹ bii…

Orileede Nijee ati Cameroun lawọn Hausa n ko ounjẹ lọ bayii o

Faith Adebọla Ija tawọn ẹgbẹ onimaaluu ati olounjẹ lawọn n ba ijọba ja lori bawọn Hausa…

Akeredolu tu ẹgbẹ awakọ ka nipinlẹ Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gomina Rotimi Akeredolu ti pasẹ titu ẹgbẹ awakọ mejeeji to wa nipinlẹ Ondo…

Ori ọkunrin kan ati obinrin kan ni wọn ba ninu mọto Hasan l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ajọ to n gbogun ti ilokulo oogun oloro nipinlẹ Ondo ti fi…

Fidio: Ayọọla Olalekan to n fi siimu kaadi lu jibiti b’ALAROYE sọrọ

Ayọọla Ọlalekan ree o, ọmọkùnrin to mọ nipa bi wọn ṣe n fi siimu kowo lakaunti…

Nitori ija Ṣaṣa, awọn Hausa ko ko ounjẹ wọ Ibadan mọ o

Ọlawale Ajao, Ibadan Ohun eelo ọbẹ̀ bíi ata, tòmáàtì, àlùbọ́sà, titi dori ẹran námọ̀ ati ẹ̀wà…

Nitori kanifa, awọn janduku ba ọpọlọpọ dukia jẹ l’Adewọle, n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin Bo tilẹ jẹ pe ọwọ ti tẹ diẹ lara awọn janduku kan to…

Ibalopọ di wahala laarin baba ọgọrin ọdun atiyawo ẹ n’Ibadan, o lobinrin naa ko foun ni ‘kinni’ ṣe daadaa

Ọlawale Ajao, Ibadan Bíi igba ti awọn eeyan naa n ṣere ori itage fawọn ero kootu…

Iya n run nimu awọn ileepo ti ko ba ta epo faraalu-Ogundoyin

Ọlawale Ajao, Ibadan O ṣee ṣe ki ijọba fiya jẹ awọn ileepo ti wọn ko ba…