Ijamba ọkọ gbẹmi eeyan meji loju ọna lleṣa si Akurẹ

Florence Babaṣọla   O kere tan, eeyan meji lo gbẹmii mi nigba ti awọn mẹta mi-in…

Gani Adams ni bi Akeredolu ṣe le awọn Fulani darandaran kuro ninu igbo ọba l’Ondo lo dara ju

Iba Gani Adams tí sọ pe ojuṣe ati ẹtọ Gomina Rótìmí Akeredolu ni lati le awon…

Láṣòrè di igbakeji ọga agba ileeṣẹ ọlọpaa Ẹkun kọkanla

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Igbakeji ọga agba patapata tuntun ti de ọga Ẹkun kọkanla ileeṣẹ ọlọpaa ti…

Ijọba Buhari fẹẹ sọ ifẹyinti awọn olukọ di ogoji ọdun lẹnu iṣẹ

Nibi ipade awọn ọmọ igbimọ ti wọn n ba Aarẹ Muhammadu Buhari ṣepade ni wọn ti…

Mọgaji agboole fa irun abẹ tẹgbọn-taburo n’Ibadan, o loun fẹẹ fi tun ọjọọwaju wọn ṣe ní

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori to fa irun abẹ awọn tẹgbọn-taburo lẹyin to tọwọ bọ wọn labẹ…

Ṣeyi Makinde atawọn agba ẹgbẹ PDP fẹẹ fi Gbenga Daniel ṣe adari ẹgbẹ naa nipinlẹ Ogun

Lati fopin sì oríṣiiríṣii wahala tó ní ṣẹlẹ nínú ẹgbẹ oṣelu PDP nipinlẹ Ogun, Gomina Ṣeyi…

Awọn ajinigbe ti tu awọn arinrin-ajo ti wọn gbe l’Ẹrin-Ijeṣa silẹ

Florence Babaṣọla Awọn arinrin-ajo meji tawọn ajinigbe ji gbe nitosi ilu Ẹrin-Ijeṣa, loju ọna Ileṣa si…

Tẹ ẹ ba fẹẹ ṣe pati l’Ọṣun, eyi lawọn nọmba tẹ ẹ gbọdọ pe kẹ ẹ too dana ariya

Florence Babaṣọla Ijọba ipinlẹ Ọṣun ti kede awọn ofin titun bayii lati dena itankalẹ arun Koronafairọọsi.…

Ipinlẹ Ogun ni Babatunde atọrẹ ti ji mọto, lasiko ti wọn fẹẹ ta a n’Ilọrin lọwọ tẹ wọn

Stephen Ajagbe, Ilorin       Ọga ọlọpaa nipinlẹ Kwara, Bagega Lawal, ni awọn afurasi mẹfa…

Adajọ ni Ademọla to lu oyinbo ni jibiti n’Ilọrin yoo ṣẹwọn

Stephen Ajagbe, Ilorin     Ọdaran ẹni ọdun mọkandinlọgbọn kan, Ademọla Adebukọla, ẹni tawọn eeyan tun…

Wọn ti bura fun Joe Biden gẹgẹ bii Aarẹ Amẹrika kẹrindinlaaadọta

Ni deede aago mẹfa ku iṣẹju diẹ ni Adajọ John G. Roberts Jnr. ṣebura fun Aarẹ…