Wọn ṣeeṣi san miliọnu meji s’akaunti Adetunji, lo ba na gbogbo ẹ, adajọ ti ju u sewọn

Stephen Ajagbe, Ilorin A ṣe oootọ lọrọ tawọn eeyan maa n sọ pe ifa a maa…

Ile-ẹjọ sọ Ademọla sẹwọn, iṣẹ ẹjẹnti lo fi lu awọn eeyan ni jibiti owo nla l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Ahamọ ọgba ẹwọn nile-ẹjọ Majisreeti to wa n’Igboṣere, l’Ekoo, sọ Adeyẹmi Ademọla si.…

Ijọba ni kawọn ilewosan maa ṣayẹwo Korona fun gbogbo alaisan to ba wa sọdọ wọn ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Ni ibamu pẹlu aṣẹ ajọ n to n gbogun ti arun, lorilẹ-ede Naijiria,…

Wọn ko gbe ọmuti ọlọpaa to pa awọn ọmọ mi meji lọ sile-ẹjọ latọdun 2015, mo fẹ idajọ ododo – Oluwatoyin

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Obinrin kan, Oluwatoyin Adetọna, ti yọju siwaju igbimọ to n gbọ ẹsun iwakiwa…

Awọn araalu ya sigboro, wọn ni ẹyin Akeredolu lawọn wa, ki awọn Fulani darandaran maa lọ

Rẹpẹtẹ lawọn èèyàn ya sita lati fẹhonu hàn l’Ọjọbọ, Tọsidee, ti wọn si sọ pe ẹyin…

Wọn ti mu Peter atawọn to ran pe ki wọn lọọ ja ọga ẹ lole n’Ifọ Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta

Ọmọkunrin ẹni ọdun mẹẹẹdọgbọn kan, Peter Okenu, pẹlu awọn mẹrin mi-in to ran pe ki wọn…

Ọkan ninu awọn tina jo l’Abẹokuta lọjọ Iṣẹgun ti ku o

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta   Ọsibitu ‘Federal Medical Center’(FMC), l’Abẹokuta, ti fidi ẹ mulẹ pe ọkan ninu awọn…

Nitori awọn Fulani, Ṣeyi Makinde ati Sunday Igboho feẹ kẹsẹ bọ sokoto ija

Dada Ajikanje Bi Sunday Igboho, ṣe bọ sita to sọ pe oun ko fẹẹ ri awọn…

Ijamba ọkọ gbẹmi eeyan meji loju ọna lleṣa si Akurẹ

Florence Babaṣọla   O kere tan, eeyan meji lo gbẹmii mi nigba ti awọn mẹta mi-in…

Gani Adams ni bi Akeredolu ṣe le awọn Fulani darandaran kuro ninu igbo ọba l’Ondo lo dara ju

Iba Gani Adams tí sọ pe ojuṣe ati ẹtọ Gomina Rótìmí Akeredolu ni lati le awon…

Láṣòrè di igbakeji ọga agba ileeṣẹ ọlọpaa Ẹkun kọkanla

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Igbakeji ọga agba patapata tuntun ti de ọga Ẹkun kọkanla ileeṣẹ ọlọpaa ti…