Ọjọ keji ti wọn ti n wa Dele, oku ẹ ni wọn ri l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko   Inu ọfọ ati ibanujẹ nla ni awọn mọlẹbi ati ọrẹ ọmọkunrin ẹni…

Christianah to gba ẹru ole l’Ekiti ti dero kootu

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Obinrin ẹni ọdun mẹtalelogun kan, Christianah Afuyẹ, ti dero kootu ilu Ado-Ekiti lori…

Sunday ati Williams ti wọn mu fun ẹsun ole jija n’Ileefẹ sọ pe loootọ lawọn jẹbi

Florence Babaṣọla Daniel Sunday, ẹni ogoji ọdun, ati ThankGod William, ẹni ọgbọn ọdun, ni wọn ti…

Toye Ajagun, gbajumọ olorin Juju kọlu Wasiu Ayinde, o loun atawọn kan ni wọn sọ orin fuji didakuda

Aderounmu Kazeem Pẹlu bi orin fuji ti ṣe da loni-in, gbajumọ olorin juju, Uncle Toye Ajagun,…

Gomina Eko tẹlẹ jade laye

Ajagun-fẹyinti Ọgagun ori-omi Ndubisi Kanu, to ti figba kan jẹ gomina ipinlẹ Eko ati Imo laye…

Nitori agidi, ọkọ kọ Basira silẹ n’Ibadan, o loun ko ṣe mọ

Oloye Ademọla Ọdunade, ẹni ti ṣe Aarẹ kootu k’ọkọ-k’ọkọ to wa ni Mapo, niluu Ibadan, ipinlẹ…

Nitori pe Fayẹmi ti kọ iṣejọba silẹ, awọn ọdaran ti gba ipinlẹ Ekiti-PDP

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ẹgbẹ oṣelu  People’s Democratic Party (PDP) nipinlẹ Ekiti ti fẹsun kan Gomina Kayọde Fayẹmi pe…

Tirela tẹ tọkọ-tiyawo pa loju ọna Ṣagamu-Ogijo

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta  Ni nnkan bii aago mẹjọ ku ogun iṣẹju, aarọ ọjọ Iṣẹgun, ọjọ kejila, oṣu…

Olori awọn aṣofin Eko gbaṣẹ lọwọ awọn amugbalẹgbẹẹ rẹ mẹrin

Faith Adebọla, Eko   Olori ile-igbimọ aṣofin ipinlẹ Eko, Ọnarebu Mudashiru Ọbasa, ti juwe ile fun…

Ọga agba ileeṣẹ ijọba ku sọfiisi rẹ n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin   Titi di asiko yii, ko ti i sẹni to mọ iru iku to…

Ẹgbẹ oṣiṣẹ kilọ fun ijọba, wọn ni wọn ko gbọdọ le awọn oṣiṣẹ ile aṣofin

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Agbarijọpọ ẹgbẹ oṣiṣẹ nipinlẹ Ekiti ti kede pe awọn ko ni i gba…