Ọmọ ale Yoruba ni ko ni i tẹle Aṣiwaju Bọla Tinubu lọdun 2023 – Oluwoo

Florence Babaṣọla Oluwoo tilu Iwo, nipinlẹ Ọṣun, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, ti sọ pe ẹnikẹni ninu…

Saheed gbe ọkada ti wọn fi ṣe e loore sa lọ, lo ba tun lọọ ji omi-in l’Owode -Yewa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   Ogunjọ, oṣu kejila, ọdun 2020, ni ẹnikan fi ọkada ṣe Saheed Bakare…

Nitori Sunday lgboho, awọn Fulani sa lọ sodọ Makinde

Ọlawale Ajao, Ibadan   Nitori bi akinkanju ọmọ Yorùbá nni, Oloye Sunday Adeyẹmọ, ẹni tí gbogbo…

Lẹyin oṣu meji ti ọkọ rẹ ku, wọn ṣa Iya Sunday ladaa pa sinu oko obi n’Ikire

Idowu Akinrẹmi, Ikire Inu Ibanujẹ nla lawọn ẹbi obinrin ẹni ọgọta ọdun ti orukọ rẹ n jẹ…

Dapọ Abiọdun fofin de tanka epo lati maa gba ori biriiji kaakiri ipinlẹ Ogun

Dada Ajikanje Lati le dẹkun iru ijamba ina to waye niluu Abẹokuta, nipinlẹ Ogun, lọjọ Iṣẹgun,…

Inu oṣu keji lawọn akẹkọọ Fasiti Ọbafẹmi Awolọwọ yoo pada sileewe

Florence Babaṣọla Awọn alaṣẹ ileewe Obafemi Awolowo University, Ileefe, ti kede pe ọjọ keje, oṣu keji,…

 Nitori ọrọ ti ko to nnkan, Falana lu mọlẹbi ẹ pa sinu oko l’Ayetoro

Adefunkẹ Adefunkẹ, Abẹ́òkúta Isaau Falana, ẹni ọdun marundinlọgọta (55), ko le sun ile ẹ mọ bayii, idi…

Nitori to ra ẹru ole, adajọ sọ igbakeji kọmiṣanna ọlọpaa sẹwọn gbere l’Ekiti

Dada Ajikanje Ilẹ-ẹjọ giga kan niluu Ado-Ekiti, nipinlẹ Ekiti, ti ju igbakeji kọmiṣanna ọlọpaa kan, Okubo…

Taofeeq lẹdi apo pọ mọ awọn oṣiṣẹ banki lati lu awọn eeyan ni jibiti owo nla…

Eeyan mẹta ku nibi ijamba ina to ṣẹlẹ l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Eeyan mẹta, mọto marun-un ati ọkada meji lo jona deeru laaarọ ọjọ Iṣẹgun,…

Wọn ti sinku Agboọla, agbẹ aladaa-nla ti awọn ajinigbe yinbọn pa n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ọsẹ meji ti awọn ajinigbe yinbọn pa a, wọn ti sinku Oluwọle…