Nitori idibo ijọba ibilẹ to n bọ, awọn tọọgi APC fi ada ati kumọ da ipade awọn SDP ru n’Idanre

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ. Lati ọjọ Isẹgun, Tusidee, ọsẹ yii ni ilu Idanre ti n gbona janjan…

Ta lo f’ọbẹ dúḿbú Oluwatoyin niluu Okuku, awọn ọlọpaa bẹrẹ iwadii nla

Florence Babaṣọla Wọn kan ba a ninu ọgbara ẹjẹ ninu ile rẹ ni. Oluwatoyin Afọlabi! Wọn…

Korona wọ ọsibitu jẹnẹra ni Ṣagamu, ogun oṣiṣẹ lo ti mu

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bi ẹ ṣe n ka iroyin yii, o kere tan, ogun eeyan ninu…

Mary sa pamọ l’Ekiti, lo ba tẹ atẹjiṣẹ sawọn obi ẹ pe wọn ji oun gbe ni  

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ekiti ti tẹ ọmọdebinrin ti ko ti i to…

Awọn akẹkọọ yari ni Kwara, wọn ni ile ti su awọn

Stephen Ajagbe, Ilorin Awọn akẹkọọ nipinlẹ Kwara l’Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii, fẹhonu han, pe awọn ko…

Ẹgbẹ akẹkọọ ṣe iwọde nitori apaayan to sa lọ lagọọ ọlọpaa n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Nnkan ko fara rọ lolu ileeṣẹ ọlọpaa to wa ni Ẹlẹyẹle, niluu Ibadan,…

Nitori ayẹyẹ ọdun Hijirah, ijọba Ọṣun kede isinmi lọla  

Florence, Babaṣọla, Oṣogbo Ogunjọ, oṣu yii, ti i ṣe ọla, Ọjọbọ, ni ijọba ipinlẹ Ọṣun kede…

Nitori ọmọ ẹyin ọkọ ti wọn lawọn TRACE lo pa a, ijọba bẹrẹ iwadii l’ Ogun  

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Latari rogbodiyan to ṣẹlẹ lanaa ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, l’Abẹokuta, nibi ti awọn awakọ…

Akẹkọọ to ni arun Korona kọ idanwo nibudo iyasọta ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Ijọba ipinlẹ Kwara ti ṣeto bi akẹkọọ-binrin ẹni ọdun mẹrindinlogun kan to ni…

Ko si aburu kankan laafin Ọọni o – Ọlafare

Florence Babasola Akọwe iroyin fun Ọọni Ogunwusi, Moses Ọlafare ti sọ pe ko si ootọ ninu…

Ọbasanjọ ti sọ iye ọdun to wu u lati lo laye o

Olori orilẹ-ede yii nigba kan, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ, ti sọ iye ọdun to wu oun lati…