Ismail Adeẹyọ Katikati lọrọ to n jade lẹnu baba ẹni ọdun mejilelogoji (42) kan, Suliman Usman,…
Author: admin
Wọn ti gbaṣọ lọrun ọlọpaa yii o, o lọọ fipa gbowo lakaunti ẹni to fẹsun kan
Adewale Adeoye Alukoro ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ, Eko S.P Benjamin Hundeyin, ti sọ pe latari ki ileeṣẹ…
Wọn ti mu obinrin yii o, awọn alaboyun rẹpẹtẹ ni wọn ba nileeṣẹ to ti n ta ọmọ ìkókó
Adewale Adeoye Awọn ọdọmọdebinrin ti wọn wa nipo iloyun, ti oyun wọn si wa ni ipele…
Ọlọpaa n wa ọmọ Hausa to fipa ba ọmọọdun mejila lo pọ n’Igbọkọda
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ondo ti fidi rẹ mulẹ pe awọn ti n tọpasẹ…
Ọmọọṣẹ Adedoyin t’adajọ ju sẹwọn wo lulẹ ni kootu
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Adeṣọla Adedeji, akọwe otẹẹli Hilton niluu Ileefẹ, ti Timothy Adegoke ba nigba to…
Eyi lọrọ ti Adedoyin sọ lẹyin ti adajọ dajọ iku fun un
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Loootọ ni owe Yoruba maa n sọ pe akọ igi ko gbọdọ soje,…
O ga o, igbeyawo awọn oṣere yii ti daru
Jọkẹ Amọri Looootọ lo ti pẹ ti awọn eeyan ti n gbe e pooyi ẹnu pe…
Eyi lọrọ ti Adedoyin sọ lẹyin ti adajọ dajọ iku fun un
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Loootọ ni owe Yoruba maa n sọ pe akọ igi ko gbọdọ soje,…
Owo iranwọ epo ni yoo rẹyin Naijiria ta o ba tete fopin si i – Shettima
Monisọla Saka Igbakeji Aarẹ orilẹ-ede yii, Sẹnetọ Kashim Shettima, ti fawọn ọmọ Naijiria lọkan balẹ pe…
Nitori ti wọn de epo mọlẹ, ijọba Kwara ti awọn ile-epo kan pa
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọgbọnjọ, oṣu Karun-un yii, ni ijọba ipinlẹ Kwara, labẹ iṣejọba…
Nitori bata lasan, ọrẹ meji gun Ekene lọbẹ pa n’Iganmu
Faith Adebọla Loootọ lawọn agba sọ pe ariyanjiyan ni i ba ọrẹ jẹ, amọ bo ba…