Tirela gba ọna ọlọna n’Ijẹbu-Ode, lo ba tẹ ẹni kan pa

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Ni nnkan bii aago mẹjọ ku ogun iṣẹju aarọ ọjọ Aiku, Sannde akọkọ ninu oṣu…

Mọto kọsitọma ti wọn ni ki Idris fọ lo gbe sa lọ l’Ekoo, ipinlẹ Ogun lọwọ ọlọpaa ti tẹ ẹ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ko ti i pe oṣu kan ti Idris Ayọtunde bẹrẹ si i ba…

Were bimọ sita gbangba l’Ọrẹ, oun lo gbẹbi ara ẹ 

Were bimọ sita gbangba l’Ọrẹ, oun lo gbẹbi ara ẹ Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gbogbo awọn to n…

Atundi ibo sẹnetọ: Tokunbọ Abiru lo jawe olubori l’Ekoo

Jide Alabi Ajọ eleto idibo, INEC, ti kede Tokunbọ Abiru, ẹni to n dije dupo aṣofin…

Ẹgbẹrun mẹta lawọn araalu yoo maa wọ reluwee lati Eko si Ibadan – Amaechi

Minisita fun ọrọ igboke-gbodo ọkọ nilẹ wa, Rotimi Amaechi, ti kede pe ijọba apapọ ti fọwọ…

Ọlọpaa ṣi n wa ọkunrin to fibinu gun afẹsọna ẹ lọbẹ pa l’Oṣodi

 Faith Adebọla, Eko Titi di asiko yii lawọn ọlọpaa ọtẹlẹmuyẹ ṣi n wa Ifeanyi Nwagboroga, latari…

Wọn ji ọlọpaa gbe ni Aba Tuntun, n’Ijẹbu-Igbo, wọn tun ba mọto wọn jẹ

Jide Alabi Titi di asiko ti a n ko iroyin yii jọ ni ileeṣẹ ọlọpaa ṣi…

Ọga ṣọja kilọ fawọn ọmọ ẹ: Ẹnikẹni o gbọdọ dabaa fifipa gbajọba ninu yin o

Faith Adebọla, Eko Olori awọn ṣọja ilẹ wa, Ọgagun Tukur Buratai, ti ṣekilọ to lagbara fawọn…

Oloye Harry Akande, oloye Ibadan, jade laye

Oloye Ayọade Akande, ẹni ti ṣe Agba Oye ilu Ibadan ti jade laye lẹni ọdun mẹtadinlọgọrin (77). Ọjọ Abamẹta, Satide, ni ọkunrin…

Wọn ṣi n wa aṣọbode tawọn onifayawọ ji gbe nipinlẹ Ogun

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Lati Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, ti awọn aṣọbọde atawọn onifayawọ ti kọju ija sira…

Awọn to pa Olufọn gbọdọ foju wina ofin – Komiṣanna Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Kọmisanna ọlọpaa ipinlẹ Ondo, Bọlaji Amidu Salami, ti ni ijiya to tọ n…