Ọlọpaa to pa Ọlaoye sotẹẹli l’Ado-Ekiti ti dero kootu

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Igbẹjọ ọlọpaa to yinbọn pa ọkunrin ẹni ọdun mọkanlelọgbọn kan, Abayọmi Ọlaoye, loṣu…

Lẹyin ti awọn onimọto din owo ọkọ ku l’Ekiti, ijọba rọ awọn ọlọja naa lati ṣe bẹẹ

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ijọba ipinlẹ Ekiti ti ṣeleri idẹra fun awọn araalu lori bi nnkan ṣe…

Wọn dana sun ole meji niluu Ileefẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn ole meji ti wọn sọ pe wọn ji ọkada lawọn araalu binu…

Tori afara ẹlẹẹkẹrin tijọba Eko fẹẹ ṣe, ọgọrun-un mẹjọ ile ni wọn maa wo

Faith Adebọla, Eko Latari biriiji ẹlẹẹkẹrin, Fourth Mainland Bridge, tijọba Eko ati ijọba apapọ fẹẹ pawọ-pọ…

Ọlọpaa bẹrẹ iwadii lori Ẹgbẹ Akẹkọọ Poli Offa to fun awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun lami-ẹyẹ

Stephen Ajagbe, Ilorin Iwadii ti bẹrẹ bayii lori iroyin kan to gba ori ẹrọ ayelujara pe…

Aburo ọkọ Tọpẹ Alabi ni: Ki i ṣe pe ẹgbọn mi ko fẹẹ tọju ọmọ ẹ, Tọpẹ lo gbe e sa fun un

*Nigba ti fiimu rẹ bẹrẹ si i ta ni ko waa gbowo lọwọ rẹ mọ n’Idumọta…

Sanwo-Olu fun iyawo awọn ọlọpaa to ku lasiko SARS ni miliọnu mẹwaa naira ati ẹkọ-ọfẹ fawọn ọmọ wọn

Faith Adebọla, Eko Awọn iyawo awọn ọlọpaa mẹfa to doloogbe lasiko rogbodiyan SARS ti dupẹ gidigidi…

Ki kọmiṣanna to ba fẹẹ dupo gomina l’Ekiti kọwe fipo silẹ – Fayẹmi

Jide Alabi Gomina ipinlẹ Ekiti, Kayọde Fayẹmi, ti sọ fun awọn kọmiṣanna rẹ pe inu oun…

Wọn ti mu ọlọpaa to gbowo lọwọ awakọ to rufin oju popo l’Ekoo

Jide Alabi Ọlọpaa kan ti wọ wahala bayii lori bo ṣe gba owo lọwọ obinrin kan…

Bisi Akande gbalejo Tinubu, Arẹgbẹṣọla ati Gomina Oyetọla, wọn ni ija ni wọn lọọ pari

Nipinlẹ Ọṣun, niluu Ila Ọrangun, ni ipade kan ti waye l’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, laarin Aṣiwaju…

Wọn tun ti ri ile mi-in ti wọn ti n ṣe òwò ọmọ tita ni Mowe

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta Lẹyin ọjọ meji ti aṣiri ile ti wọn ti n ta awọn ọmọ…