Faith Adebọla, Eko Ile-ẹjọ giga tijọba apapọ to fikalẹ siluu Ikẹja, l’Ekoo, ti ni ki awọn…
Author: Alaroye
Ile-ẹjọ tu nọọsi ti wọn lo ṣeku pa Sẹnetọ Isiaka Adeleke lọjọsi sile, wọn ni ko mọ nnkan kan nipa rẹ
Dada Ajikanje Ile-ẹjọ giga kan nipinlẹ Ọṣun ti fidi ẹ mulẹ pe nọọsi kan, Alfred Aderibigbe,…
Ọmọ ẹgbẹ okunkun ya bo ileewe girama l’Ọrẹ, ni wọn ba tu awọn akẹkọọ ka nibi ti wọn ti n ṣe idanwo lọwọ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Kayeefi lo ṣi n jẹ fawọn eeyan Ọrẹ, nijọba ibilẹ Odigbo, pẹlu bawọn…
Igbimọ to n gbọ ẹsun ifiyajẹni SARS bẹrẹ ijokoo l’Ondo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Igbimọ tijọba ipinlẹ Ondo gbe kalẹ lati gbọ ẹsun gbogbo awọn ti ọlọpaa…
Ọlọpaa ṣawari awọn ọmọde mẹwaa ti wọn loyun ni Mowe, obinrin kan lo n ta awọn ọmọ ti wọn ba bi
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ile kan wa lagbegbe Ọfada si Mowe, ni ipinlẹ Ogun, awọn ọmọbinrin tọjọ…
Nitori eto aabo to mẹhẹ, egbẹ agbaagba ilẹ Hausa ni ki Buhari kọwe fipo rẹ silẹ
Dada Ajikanje Latari ipaniyan ati ọpọlọpọ itajẹsilẹ to n lọ kaakiri lorileede yii, paapaa ju lọ…
Wọn ni ina ẹlẹntiriiki to ṣẹju ati jẹnẹretọ lo fa ijamba ina to ṣọṣẹ ni Gbagada
Faith Adebọla, Eko Bo tilẹ jẹ pe inu ibanujẹ nla lọpọ awọn to padanu dukia wọn…
Emi o ba Gani Adams ja o, iwa rẹ ni ko ba temi mu -Ọbasanjọ
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Olori orilẹ-ede yii nigba kan, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ, ṣabẹwo si ọkan ninu awọn…
Wọn gun gende kan pa, ọpọ eeyan tun fara pa ninu ija igboro n’Ibadan
Ọlawale Ajao, Ibadan Gende Ọlọrun kan lo fo ṣanlẹ to ku, nigba ti ọkẹ aimọye eeyan…
Dapọ Abiọdun gbe iṣuna ọdun 2021 kalẹ fawọn aṣofin
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta Gomina ipinlẹ Ogun, Ọmọọba Dapọ Abiọdun ti gbe aba eto iṣuna ipinlẹ yii…
Awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun Ikorodu kọju ija si t’Odogbolu, lawọn ọlọpaa ba ko wọn
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta Mẹrin ninu awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun ti wọn n da Ikorodu, niluu Eko…