Idris atawọn ọrẹ ẹ pa manija ileepo n’Ikire 

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn afurasi mẹrin ti wọn lọwọ ninu iku manija ile-epo kan niluu Ikire,…

  Pasitọ Adebayọ si tan akọrin ṣọọṣi rẹ wọ yara, lo ba  fipa ba a lo pọ l’Agbado

Faith Adebóla Egbirin ọte, ba a ṣe n pa’kan lọ’kan n ru, lọrọ ifipa ba ni lo pọ to n waye lemọlemọ laarin awọn ojiṣẹ Oluwa…

Nitori Tinubu, Fayẹmi ati Omiṣore tun ṣepade pẹlu Wike ni London

Faith Adebọla  Ko jọ pe aawọ to n lọ lọwọ ninu ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party,…

Owolabi ji mọto mama ẹ gbe, ibi to ti fẹẹ ta a ni wọn ti mu un

Faith Adebọla, Eko Bi ki iba ṣe pe ẹnu Alukoro ileeṣẹ ọlọpaa Eko lọrọ naa ti…

Irin oju ọna Reluwee lawọn eleyii lọọ ji tu tọwọ fi tẹ wọn ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Akolo ajọ ẹsọ alaabo sifu difẹnsi, ẹka tipinlẹ Kwara, ni awọn adigunjale meji…

Ọṣun 2022: Agbẹjọro agba mẹjọ, lọọya mejidinlaaadọta ni yoo ṣoju Adeleke – Alimi

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ofuutufẹẹtẹ ni ẹjọ ti Gomina Oyetọla ati ẹgbẹ APC pe lati ta ko…

Abẹẹ ri Mato, ọmọọdun mẹta lo fipa ba lo pọ

Faith Adebọla  Akolo awọn ọlọpaa ipinlẹ Bauchi, nibi ti wọn ti n ṣewadii awọn oniṣekuṣe atawọn…

Ọgọrun-un kan miliọnu lawọn to ji Kazeem ati iyawo ọmọ ẹ gbe n beere n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin  Ọgọrun-un kan miliọnu Naira lawọn agbebọn to ji Kazeem Asalapa ati iyawo ọmọ…

Kome n tẹẹsi ibọn ẹ tuntun, lo ba fi pa ọmọ ọdun mọkanla

Faith Adebọla Ko sọna ti Kome Ọgaga, iyẹn ọkunrin tẹ ẹ n wo fọto ẹ yii, ko fi…

Lati Eko ni Ṣẹgun atọrẹ ẹ ti lọọ ji ewurẹ gbe n’Ibadan tọwọ Amọtẹkun fi tẹ wọn

Jọkẹ Amọri Lati adugbo Alapẹrẹ to wa ni Ketu, niluu Eko, ni awọn ọrẹ meji kan,…

Lẹyin ọjọ kẹka ti wọn n wa wọn, wọn ba oku akẹkọọ meji nihooho ni KWASU  

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọ Abamẹta, Satide, ọsẹ to kọja, ni wọn ba oku ololufẹ meji kan,…