Adigunjale ya wọ ile awọn akẹkọọ Poli Ilaro, wọn ba awọn akẹkọọ-binrin wọn lo pọ

Monisọla Saka Koju ma ribi, gbogbo ara loogun ẹ lawọn akẹkọọ Poli Ilaro fi ọrọ naa…

Tori bi awọn akẹkọọ ṣe fipa ba ẹlẹgbẹ wọn lo pọ, ijọba ti ileewe Chrisland pa l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Ijọba ipinlẹ Eko ti fi agadagodo gbangba sẹnu ọna to wọ ọgba ileewe…

Awọn agbebọn yinbọn pa awakọ nibi to ti n sa fawọn ajinigbe l’Akunnu Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọpọ awọn eeyan ilu Ajọwa Akoko, nijọba ibilẹ Ariwa Iwọ-Oorun Akoko, ni wọn…

Awọn ọmọlẹyin Akeredolu binu sawọn to n gbe iroyin iku rẹ kiri

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ko jọ epe, bẹẹ ni ko jọ aṣẹ, lo n jade lati ẹnu…

Iya mi lo maa n ro mi lagbara nigbakuugba ta a ba fẹẹ lọọ digunjale- Timileyin

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Kayeefi nla lo jọ loju awọn to wa nibi ti ọmọdekunrin ẹni ọdun…

Awọn Fulani kọ lu baba agbẹ ninu oko rẹ n’Ikakumọ Akoko, wọn gun un yannayanna

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Baba ẹni ọdun mẹtadinlọgọrin kan, Alagba Babatunde Benjamin, lori tun ko yọ lọwọ…

Ẹgbẹ APC yoo ṣepade lori eto idibo abẹle wọn ni ogunjọ, oṣu Kẹrin

Monisọla Saka Ẹgbẹ All Progressive Congress (APC), ti fẹnu ko lati pade ni ogunjọ, oṣu Kẹrin,…

Awọn alakooso LCC sun ọjọ ti wọn yoo bẹrẹ si i gbowo ni toogeeti Lekki siwaju

Monisola Saka, Eko Lẹyin ọpọlọpọ ijiroro pẹlu awọn lookọ lookọ, ileeṣẹ to n mojuto toogeeti to…

Ọwọ tẹ Ṣakiru atọrẹ ẹ lasiko ti ọn fee ji ọmọ meji gbe ni ṣọọṣi Sẹlẹ l’Abẹokuta

Gbenga Amos, Abẹokuta Bo tilẹ jẹ pe ori ko afurasi ọdaran ti wọn porukọ ẹ ni…

Ọmọọdun mẹtadinlogun gun ọga ẹ pa, ibi to ti fẹẹ ta mọto ẹ to ji lọwọ ti tẹ ẹ ni Benin

Faith Adebọla Wọn lọjọ ori ọmọkunrin yii ko ju mẹtadinlogun lọ, ṣugbọn iwa buruku to hu…

Tori ifipabanilopọ, wọn sọ Micheal sẹwọn gbere l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Pẹlu bi agbẹjọro Ahmed Micheal, baale ile ẹni ọdun mẹtalelọgbọn ti wọn fẹsun…